Itoju oloyun

Itoju oloyun We treat all kind of infection,we give pure organic solution to all kind of disease

28/12/2025

Fun awon ti won o tete ri igbe ya
Koro osan Ka lo Ka fi po ori ki a fi owu kekere KO Ka ti Bo oju idi lale

27/12/2025
26/12/2025

OGUN FUN OYUN TI KO YO
Eresile ewe lapalapa, igi gbaguda ti o ba da funra re, padi atare kan, a o Jo gbogbo re papo, a o ro sinu ado, obinrin naa yio maa fifo eko tutu mu die die. A baa yin Lara mu.

ITOJU AISAN INU KIKUN FUN ENITI INU RE MA NKUN NI GBIGBO IGBAA o fi omi osan wewe glass cup kan gbo ewe efinrin, a o fi ...
26/12/2025

ITOJU AISAN INU KIKUN FUN ENITI INU RE MA NKUN NI GBIGBO IGBA
A o fi omi osan wewe glass cup kan gbo ewe efinrin, a o fi ase se omi re, a o maa mu ni sibi merin ni aaro, osan ati ni ale.
IKILO :- Alaboyun ko gbudo lo iru ogun yi o.
Ki eniti o ni ulcer ma lo o

26/12/2025

OGUN FUN OBINRIN TI OMU NDUN
E lo wa ewe marugbojiyan, ki e gun papo mo ose, ki e maa fi we omun naa.
AKIYESI ---- E koko fi epo pupa ra omu naa fun iseju mewa ki e to fi ose yi foo, leyin ti e ba we omu naa ta, e je ki omi yen gbe mo lara. A baa yin lara mun.

20/12/2025

alagbo

19/12/2025

REPOST
OGUN FUN OKUNRIN TI ATO RE SAN KO LE KI
Ikun ipado, a o ge sinu igo, a o da oyin igan si, a o ki igi opa osunsun sinu re, a o gbe pamo fun ojo meta, leyin ojo keta ki okunrin naa maa fa opa ti o wa ninu igo naa sita, ki o maa la ni aaro, ki o tun da opa yen pada sinu igo naa, ti o ba di ale ki o tun fa opa naa to ki o maa la, bi a se maa lo Ogun yi niyen o. Titobi Olorun wa ni ara re.

19/12/2025

REPOST
OGUN EDA FUN OBINRIN
Ewe ina pupa, emo ajao, ose dudu, a o gun papo, ti Obinrin naa bati ri alejo re ni yio bere si fi ose yi we abe re t**i di igba ti alejo re maa lo.
ILILO : - Ti alejo obinrin naa bati lo, ko gbudo lo ose yi mo o. Adura gbogbo wa maa gba o.

Address

Abeokuta

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Itoju oloyun posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram