30/10/2025
Ògún Awure Ajé Tó Dájú Kíákíá
Èmi ọmọ yín ná ní òò orúkọ mí kòsì yipada ÌṢẸṢÉ LÁGBÁ Àdúrà ẹní kánkán wá yíò gbà láṣẹ Elédùmarè irè 🙏🙏🙏
Isẹ yí dára pupọ ẹyín ènìyàn mí ẹ má fí Isẹ yí ṣeré óò, Ògún tí ó jẹ Èwe rẹ lo kú kán
Ẹ bámí sisẹ yí óò kó ná yín lówó
Yíò jẹ́ fún ẹnì kánkán yín láṣẹ Elédùmarè 🙏🙏🙏
Ẹ bámí share Iṣẹ yí kakiri kí àwọn ẹlòmíràn lè jẹ ànfàní rẹ ọwọ́ tí ẹ fí ń share Isẹ yí ẹ ní fí ọwọ yín ná gbé ọmọ sìn láṣẹ Elédùmarè 🙏🙏🙏
Isẹ ná rè ẹyín ènìyàn
Èwe mẹsẹnmẹsẹn, Èwe Isẹpẹn Àgbè, òbí alawẹ mẹ́fà, Ào lọ wọn pọ pẹ̀lú ata ìjọsì díẹ̀,Ào fí Ẹjarọ ńlá ṣe,èpò, iyọ̀, Ào fí sì,tí ó bá jìnà tán,Ào sọ sórí ǹkan,Ào fí iyerosu tẹ ifá èjì ogbe ,Ào wá dà sínú Asejẹ́ ná, Ào wá ṣé Àdúrà sì bí aṣé nfẹ, Ào wá jẹ́
FÚN ẸYÍN TÍ Ẹ KÍ ǸJẸ́ ẸJARỌ
Ẹ lọ wá Ìgbín àgbò kán, mariwo ọpẹ, ewé ẹla, Ào lọ pẹ̀lú ata ìjọsì díẹ̀, Ào wá fí Ìgbín yẹn ṣé jẹ́ pẹ̀lú Àdúrà
Yíò jẹ fún yín láṣẹ Elédùmarè 🙏🙏🙏
Fún iwọ tí o nwa Promotion Tàbí Obínrin tí o nwa Ọmọ bíbí lati ọjọ́ Pipẹ,Tabi Obínrin ti Ọkọ Ọrùn ndá lamu,Fun Ajo Ajé, Fún Court case,,Lati má rí Ànu gbà dada, Fún Promise and Fail, Fún Ìkọ Asmar, Láti má rí Ojurere làti ọwọ́ Ọgá, Láti lówó kíákíá Fún Iwọ tí o ntà ọjà, fún travel, Ànu Alanu, Awọro Ọjà, Ọba Ẹyọnu àti bẹbẹ lọ. e.t.c Ẹ pèmí sórí number yi tàbí kí ẹ message mi lori Whatsapp number mi 09065621220.