21/04/2021
E kaaro ninu yara yi o, moki gbogbo wa patapata, adura wa yio ma gba o. Asiri wa koni tu, ori wa koni gbabode iseda wa koni gbabode. Aanu olorun ati abo re yio daju lori wa o. Motun gbe tuntun de laaro yi. Hmmm, asiri ju ogun lo. Awa na gbiyanju die ninu aye.
ASIRI OWO BIBO KIAKIA TODAJU LAARIN OJO META SI MEJE.
A o lowa agbon toba lomi ninu daada meta, rice tutu agolo milk kan, isasun tabi pot to clean daada, milk olope agolo kan, Bible.
Sise re, a o jo omi agbon meteta yi sinu ike kan, a o gbe pot kana, toba ti inu re bati gbe, a o da omi agbon na si, ti omi na bati ho, a o da rice yen si lai fomi sin rara. A o fi omi agbon na se jina. Toba jina tan, a o so sori ibikan. A o si ideri re, a o sadura si wipe ki asiri wa bo lonakona laarin ojo meta si meje. A o si Bible wa, a o ka Psalm 25, a o tun sadura si, a o tun ka Psalm 71, a o tun sadura si, a o tun ka Psalm 121. A o tun sadura si. A o ni suuru kofi tutu daada, a o wa fi owo je rice na. Ti aba ti je tan, leyin wakati kan, a o lu milk olope na, a o gbe si enu, a o mun tan lekana lai gbe enu kuro nibe t**i afi ma mun tan. A o fi awon agbon na se saara tabi ki a lo dawon sonu. Kosi eni ti kole se asiri yi. E jeki agbon ti eba lo lomi ninu daada, ki rice yen bale jina daada, ki o bale rorun lati je. E maje ki n royin re. Hmmmm, e danwo. E jeki a mafi emi imoore han lori awon ise ti eba n dawon, nkan ti ako ba jiya fun ki toojo. Pls call me on 08150972851.