Arojinle on Real Message TV

Arojinle on Real Message TV HERBAL MIXTURE & CARE, TRADOMEDICAL, ALL HEALTH CARE, CONSULT, HERBALIST, All illness Solution & Cure

AWURE TOJEẸ BI IDAN.Erẹlẹ ewe ọdan arin ọja Ẹyẹle funfun Kan 1odidi atare kan 1ao la aya ẹyẹle Ao ko ewe ati atare sinu ...
02/04/2026

AWURE TOJEẸ BI IDAN.

Erẹlẹ ewe ọdan arin ọja
Ẹyẹle funfun Kan 1
odidi atare kan 1

ao la aya ẹyẹle Ao ko ewe ati atare sinu yẹn si ao ran pada,

O di jijo pọ lẹyin jijo ao wa po lọ ọsẹ dudu ao ko sinu igba olomori

ao depa fun ọjọọ merindinlogun 16days ki a to bẹrẹ sini wẹ ni aro laro.

🤍✌️ KOJU BẸ YẸN LỌ! ✌️🤍


👉👂

IRE O 👋

01/04/2026

ELEYI ISORA NINU EWUKEWU

ỌSẸ AWURE FUN ONISẸ ỌWỌ TABI ONISOWOewe owu akẹsẹ oojọike funfun omoriose dudueja ojiji ao gun ewe owu naa mo ọsẹ dudu t...
31/03/2026

ỌSẸ AWURE FUN ONISẸ ỌWỌ TABI ONISOWO

ewe owu akẹsẹ oojọ
ike funfun omori
ose dudu
eja ojiji

ao gun ewe owu naa mo ọsẹ dudu ti yoo kunna dada, lẹyin eyi a o mu eja ojiji YẸN sinu ike funfun naa.

ao wa ko ỌSẸ dudu ti a gun yẹn le Lori mọlẹ daaadaa,

Lẹyin naa ao wa fi ideri ike naa de lori,

Ao si gbe pamọ fun Ọjọ mẹta 3days

Lẹyin ọjọ kẹta

odi wiwe ni laraarọ pẹlu adura

🤍✌️ KOJU BẸ YẸN LỌ! ✌️🤍

👉👂

IRE O 👋

29/03/2026

ÀGBO ÌTÚWỌ́ AYÉ
Ewé àjéòbàlẹ́ tútù
Ewé oríjìn tútù
Ewé ìyálóde funfun tútù
Aó fi omí gboó, aó fi omí àgbo náà sanra lásán.

ASEJẸ AWURE TODAJU BIKUỌga ibilẹ gbigbẹ kan 1Ewe sawerepepe tutu diẹ Iru diẹ Ata ijọsin diẹẸyin ororo Mẹta 3Owo paper  #...
28/03/2026

ASEJẸ AWURE TODAJU BIKU

Ọga ibilẹ gbigbẹ kan 1
Ewe sawerepepe tutu diẹ
Iru diẹ
Ata ijọsin diẹ
Ẹyin ororo Mẹta 3
Owo paper #200 Kan
Ori diẹ

SISE RẸ :

Ao lọ Oga ati iru ati ewe sawerepepe ati ata ati owo paper LỌTỌTỌ,

ao da sinu abo kan, ao fọ awọn ẹyin si, ao po papọ, ao gbe koko ka ori Ina ti oba ti gbona daaadaaa ao ju ori yi si ti yọ, ao da gbogbo eroja ti apo papo sinu abo yi sinu ape ninu ori yii, ao fi ori yii din je ni aseje, ti oba jina,ao so sori Osuka ao se adua iwure, si ao ko jẹ.

ODAJU BIIKU

28/03/2026
27/03/2026
ASINA AWAN ÀGBÀLAGBÀ very very OK...Eiye kowe tope 1Eiye owiwi tope 1,Eran ewure ooue toje abo tí koiti bímọ rí toje dúd...
26/03/2026

ASINA AWAN ÀGBÀLAGBÀ very very OK...
Eiye kowe tope 1
Eiye owiwi tope 1,
Eran ewure ooue toje abo tí koiti bímọ rí toje dúdú, aoge orí rẹ sínú agbada, aojopo má awan eroja toseku, aolo kúnna, aoro sinu ado àto tí àti rán ni àwo ẹkùn, igi atorin ni aofi di ẹnu àto yẹn, aoma lo pelu oti ni araaro,
Aopin ẹran yoku ni sára, eniti òní ogún yí kogbodo je nibe
Tí ọba dini every Thursday ni ale, aoma ro ekuru funfun pelu rẹ, aoje die nibe, ao fan ìyókù síta fun awan àgbàlagbà...
Ogun na odaju pupọ.

ÀKÍYÈSÍ PATAKI... Ti aba bere sini lo ogún yí awan ebi wá, wan yio ma wá iranlọwọ pàtàkì wá fún wa, aogbodo ṣe ahun sì wan, iwanba tí abani lágbára kí ama fún wan, tí a base ahun, ogun Yi kọ́ni sise Bose yẹ kosise.

25/03/2026

OGUN AWISE INU TAN FI NBE OLORUN

ATÚDÈ ÌPỌ́NJÚEgbò túdèÌsáwùrú tó lọ́mọ nínú kanÈèpo ọ̀bọ̀Ata ìjọ̀sì níwọ̀nbaAó gun mọ́ ọṣẹ dúdú. Fífi wẹ lálẹ́.ỌFỌ̀ RẸ̀Ì...
25/03/2026

ATÚDÈ ÌPỌ́NJÚ
Egbò túdè
Ìsáwùrú tó lọ́mọ nínú kan
Èèpo ọ̀bọ̀
Ata ìjọ̀sì níwọ̀nba
Aó gun mọ́ ọṣẹ dúdú. Fífi wẹ lálẹ́.
ỌFỌ̀ RẸ̀
Ìlẹ̀kùn ti ìsáwùrú bá tì, omi tútù nii síi. Túdè, wá tú èmi L ọmọ L sílẹ̀ loni ninu gbogbo ìde ati ìdààmú ayé gbogbo.

24/03/2026

ẸYỌNU AYE TOJINA

Ori aparo kan 1
Ewe apada mẹta 3
Ọkọ atare kan 1

ao gun won papo, ti a ba gun papọ tan ao da si inu lọfinda bintu tabi
eyikeyi

ao ma fi para.

🤍✌️ KOJU BẸ YẸN LỌ! ✌️🤍

👉👂

IRE O 👋

23/03/2026

MAKANJU OO

MASARE OOO

SUNGBON MADURO OOO

Hmmmmm asiri loba OGUN

Dan Asiri yi wo kofun Ile labo ,WA Mon wipe ASIRI siwa toun je daada

ASIRI ITUWO AYE KIA KIA LESEKESE

08062919475

Address

B 69 OLUWOMI AREA ILOBU TOWN
Ilorin

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Arojinle on Real Message TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram