05/04/2024
TIWA N TIWA… Tiwa á dára 🤲
WE MAY NOT POST ON FACEBOOK FOR SOME DAYS OR WEEKS, BUT WE ARE BUSY OFFLINE.
(Think about it) 🧠
BÍ OLÓRUN BÁ KÁDÀRÁ WÍPÉ KÍ O KA ÀTÈJÍSE YÍ DÉ ÌPARÍ, WÀÁ RÍ TÌE MÚ NÍBÈ 👌.
Nígbàkan, èyin yóò rí mi. Nígbàkan, èyin kì yóò rí mi.
Ìwo dúró de àsírí / ètò awoof orí àwon Facebook groups tàbí Tiktok pages tí o wà káàkiri láti jé ènìyàn nínú ayé.
Sé eni tí kò bá mo ibití egbé rè ti ń là, eré lásán ni yó ma sá kiri lójú-ònà tí òun gan kò mò.
Bí eré, bí eré, nnkan sì bàjé lo mó e lówó, béè ni nnkan rere ń sonù, oò sì sonú, oò fura
🙆♂️!
Ó wá ń so wípé àmúwá Olórun ni. Káì! Ìwo ò tíì ka Bíbèlì e débi wípé gbogbo nnkan tí Olúwa dá, dáradára ni? Níbo wá ni àìda ti wá? Ìwé mímó so wípé “òtá ni ó se èyí”.
Mo ti máa ń so fún yín wípé kò ye kí òjògbón gba kámú sínú ìyà, ìsé àti òsì (tàbí àdánwò tí kò tée lórùn). onígbìyànjú gbodò wá ònà àbáyo láti sún síwájú. Nítorí àwon tí kò sùn (sleep) ti gba oore ojúmó tí wón ti fón síta lógànjó-òru tán.
Isé N10k, N20k ni kí o máa wá kiri láti fi fi di Millionaire, pèlú bí gbogbo nnkan se wón tó yí, tí èròjà náà ti wón. Ayé gan ti sún kúrò ní bí e ti lérò pé ó wà télè.
Gbogbo òògùn kó lo lè se fún ara re, eni tó mo ojú Ògún ní pa Obì nírè. Bóyá lo mò wípé májèmú ìpè eni tó se òògùn fún náà máa ń ran òògùn lówó 😊.
Eè gbó, èèkòòkan tí owó bá dilè la máa ń ráyè post Remnants àti àwon àsírí kéékèèké sórí Facebook fún àwon ara Facebook groups association 😂. Sé níbi tí àwon oníjìbìtì ti pò káàkiri orí social media tí wón ń copy isé wa káàkiri different platforms láti lo máa fi form ògá Boss tàbí lu àwon ènìyàn ní jìbìtì, ni òjògbón kan á wá fi gbogbo ààyè rè máa fi post àwon ojúlówó àsírí pómbélé tó rìn nínú ayé (tí òun náà fi ń jeun) fún thousands of online sc@mmers tí wón lúgo káàkiri inú groups.
Jé kí n sáré gbé e débè tán…
Njé ìwo mò wípé òpòlopò ìgbà ni wón ń gba oore tó tó síe lo? Ó wá ń so pé “omi tí èdá bá máa mu, kò ní sàn kojá enu rè”. Dey play… 😂
Hmmm…
O mo iye èyin tí e jo ńse irú Business kannáà sùgbón tó jé wípé òjà Mummy Hammed nìkan ni gbogbo ayé ń fé bá ra ojà?
Ìwo tóo jé omo G, njé customer (cl) re ti lo sí store láti fi owó isé rètí o ti ńse ráńsé sí o (gift cards) but elòmíràn ló padà send rè sí 😂?
Mummy, èyin ni oko yín bá se ìgbéyàwó, sùgbón nisinyi, èyin àti àwon omo tí e bí fún jagunlabí kò rí ojú rè nílè mó. Omoléyìn re tí ìwo fà lówó sókè ló ń gba gbogbo contracts mó ìwo lára, oò sì fura.
Ìyen ni wípé ìjoba-òrun ti di à fi agbára wò, àwon alágbára (onígbìyànjú) ti fi agbára gbàá lówó eni tí kò mòó lò. Hmmm… Gbogbo àwon tí e jo se Orò ló ti kìje, wón ti lo mó e lára. Lékeléke kò ní mú Àparò dé ibi tó ti ń fo A*o tirè láíláí.
Tó bá ko ojú síe, taá! Tó bá ko èyin sí e, taá! Tó bá ku ìwo nìkan, ronú sì òrò mi dáadáa.
Njé e mò wípé tí e bá mú ewé Mútèmirò òòjó, tí e gún-un pò mó Ose dúdú, tí e wá fi èjè eran Èdè tí wón pa lóòjó pòó, ti e bèrè sí ní wèé láràárò, eó ma bá àánú pàdé?
Ìwó tí o bá n we Ose yí, àsírí á máa bò fún owó níná. Sùgbón má gbàgbé wípé ilè làá kókó tè, ká tó te Ení o. Kí ònà oore ó tó sí fún o, njé kò sí owó àwon hmmm… tàbí ogun lára re? Òògùn síse ní ètò.
Àwon tí òye wón bá sí ní àkókò yí ni mò ń báwí, á kò rán mi sí gbogbo ènìyàn, nítorí Ó ní “èmi yóò sàánú fún àwon témi yóò sàánú fún”. Ààbò òrò ti tó fún omolúàbí.
Èmi ni tiyín tòótó,
Prophetic Dr. Agboolá Opéyemí
(Bàbá Orísun International)
Eni tí ò ní mi, kò léèyàn o.