YARA ASIRI AYÉ

YARA ASIRI AYÉ Òlayimika herbal centers remedies yara asiri ayé lati leso awon ohun asiri awon agbalagba ni ayé atijo lati fiṭa òmò arayé loré
07047314225

EYONU AGBO ÒLA  MIORAYE ASODUN RARA AMON GBOGBO ÉYIN TI ÉMA COPLAIN WIPE ÒSÉ DUDU KOBAYIN SISÉ RARA ÉLOBAMI GBIYANJU ASI...
23/02/2026

EYONU AGBO ÒLA

MIORAYE ASODUN RARA
AMON GBOGBO ÉYIN TI ÉMA COPLAIN WIPE ÒSÉ DUDU KOBAYIN SISÉ RARA ÉLOBAMI GBIYANJU ASIRI WO ÉLÉDUA AJÉ KOBAYIN LARAMU OO

Isénani ooo 👇👇👇
Ao ko agbon meta sinu ikoko tuntun, ao fi Eyin Ororo kan si Larin, Ao wa da Ewe akoko le lori, Pelu omi, Ao gbe kanan, Leyin toba jina, Ao da omi Agbo yen sinu Ike iwe, Ao fo Agbon yen si agbo na, Ao lo fi we, Ao je eyin yen ti Aba fe lo we, iwe yen amon siwaju ki étodawole ékoko bami share réna tori kini kankan ko tori anfani awon élomiran nani kiwon lebaje anfani isénani ooo

EYONU TO DAJUBi o ba se igba eniyan won yio dari jin e lagbara olorun Mioraye asodun rara ewe aanu, ewe orijin, ewe ooyo...
23/02/2026

EYONU TO DAJU

Bi o ba se igba eniyan won yio dari jin e lagbara olorun Mioraye asodun rara ewe aanu, ewe orijin, ewe ooyo, ewe ajeofole, ao toju epo pupa die, ori die, adi die, ao gbe won sinu oorun lotooto ti won o fi yo tan. Ao gun gbogbo eroja yen papo pelu ose dudu ao wa kan die die ninu epo, ori ati adi yen si, ao po papo amon siwaju ki èto dawole ékoko bami share réna tori kini kankan ko tori anfani awon élomiran nani kiwon lebaje anfani isénani ooo

Pelu gbolohun ré. 👇👇👇👇

ewe olusaanu loni ki e saanu mi, ewe orijin loni ki e foro temi jinmi, ewe ajeofole loni ki oran gbogbo o fomi ru, ooyo loni ki e maa yonu simi, bi epo ba foju kan oorun ti inu re yo ni, bi ori ba foju kan oorun ti inu re yo ni, bi adi ba foju kan oorun ti inu re yo ni.

Anfani siwafun éyiti ékobalesé iséyiyi fun arayin aleranyin lowo lori é call my number or msg me on Whatsapp 07047314225

Follow my page lati lejé awon anfani isémiran

Majẹmu rẹ ṣe adua funmi wipe mionifi OJUSUKUN òmò ati éyin na oooo

👉Fún ibẹrẹ Abi ọna abayọ lórí èyíkéyìí ogun TODOJU ko ooo
07047314225

👂Gbogbo aiye lowa tatise ( ayẹwo ) lati 12:00 t**i di 4:00pm details to send full name ( ayewo ) nipa igbesi aiye ( dm ) 07047314225

👉MAWO aiye rẹ ran ,made isoro re Mara ooo,masu , koba le sun

Message me WhatsApp or call me
07047314225
👇 Awọn iṣẹ yi wale ni tita ooo 👇
07047314225

EYONU TODAJU Ao fi aadun elepo Ati odidi atare kan tele ape, ao wa kewe Ooyo ibile pupo lelori ao jopo aolo sugar onikor...
22/02/2026

EYONU TODAJU

Ao fi aadun elepo Ati odidi atare kan tele ape, ao wa kewe Ooyo ibile pupo lelori ao jopo aolo sugar onikoro iiyekiye mo.Ao maala ni owuro kutukutu amon siwaju ki étodawole ékoko bami share réna tori kini kankan ko tori anfani awon élomiran nani kiwon lebaje anfani isénani ooo

ASINA  TI O CONFIRM               Mioraye asodun rara adan  1, obe 1, obi ajopa 1, atare odidi 1, ajopo ama fifo eko mu ...
22/02/2026

ASINA TI O CONFIRM

Mioraye asodun rara

adan 1, obe 1, obi ajopa 1, atare odidi 1, ajopo ama fifo eko mu lago kan oru, ama fi eyin tilekun ti aba nfo lowo ti a fi mu tan pelu gbolohunré. Amon siwaju ki étodawole ékoko bami share réna tori kini kankan ko tori anfani awon élomiran nani kiwon lebaje anfani isénani ooo
🦻🦻🦻🦻🦻🦻
agbasi agba ti, bi oso batilekun aje ni nsi, bi aje ati oso batilekun emere ni nsi, bi oso,aje ati emere batile eledumare ni nsi,ki ilekun ola,owo,omo,ifokanbale, igbega......, ki o wa si funmi.awamu

Anfani siwafun éyiti ékobalesé iséyiyi fun arayin aleranyin lowo lori é call my number or msg me on Whatsapp 07047314225

Follow my page lati lejé awon anfani isémiran

Majẹmu rẹ ṣe adua funmi wipe mionifi OJUSUKUN òmò ati éyin na oooo

👉Fún ibẹrẹ Abi ọna abayọ lórí èyíkéyìí ogun TODOJU ko ooo
07047314225

👂Gbogbo aiye lowa tatise ( ayẹwo ) lati 12:00 t**i di 4:00pm details to send full name ( ayewo ) nipa igbesi aiye ( dm ) 07047314225

👉MAWO aiye rẹ ran ,made isoro re Mara ooo,masu , koba le sun

Message me WhatsApp or call me
07047314225
👇 Awọn iṣẹ yi wale ni tita ooo 👇
07047314225

"ASINA OWO KAN REO" GBOGBO  ÉYINTI ÉSO WIPE ASIKOYIYI LÉ BÉNI LOTO AMON BI OSÉLÈTO NI ÉLOMIRAN GBÉ IKANGIDISÉ NINU AYÉ R...
21/02/2026

"ASINA OWO KAN REO"

GBOGBO ÉYINTI ÉSO WIPE ASIKOYIYI LÉ BÉNI LOTO AMON BI OSÉLÈTO NI ÉLOMIRAN GBÉ IKANGIDISÉ NINU AYÉ RÉ HMMM GBOGBO ÉDA TI OBANI OWOLOWO YALA NINU ORÉRÉ TABI AWON ÒMÒ IYA RÉ LEYIN KIWON FUN Ò NI OWO TI OMATO OO JEHUN KOSI ÉYITI OMASO FUN Ò WIPE ASIRI ÒLA OHUN NI OOO IWONI KI OJA RARÉ OOO ÒRÒ DIÈ OTITO FUN ÒMÒ LUABI MAJARÉ OO OJUKAN NI KI OWA BI OMI ODAGUN MAJARE OO
Éyin éniyan mi étarasasa lobami gbiyanju asiriyi oo
👇👇👇
Ewe Feyinbisowo, Ewe kitipon òla 41, Ao lo paapo mo iyere iyekiye, Ao pa Eiyele Funfun, Ao du Eje Re yen sinu Isasun pelu omi Tati ka, Yahtiya Risikua Roggadan Minkuli monkani Walau Khaeru Rosikinna 41, Ao ge eyele yen si 16, ao se je odaju nio, Taba fe ko tun sise taara, Gbogbo nkan toku lara eyele yen, ao jopo mo atare, ao lo, ao wa po mo ose dudu, ao ma fi we. Odaju ni oooo

Anfani siwafun éyiti ékobalesé iséyiyi fun arayin aleranyin lowo lori é call my number or msg me on Whatsapp 07047314225

Follow my page lati lejé awon anfani isémiran

Majẹmu rẹ ṣe adua funmi wipe mionifi OJUSUKUN òmò ati éyin na oooo

👉Fún ibẹrẹ Abi ọna abayọ lórí èyíkéyìí ogun TODOJU ko ooo
07047314225

👂Gbogbo aiye lowa tatise ( ayẹwo ) lati 12:00 t**i di 4:00pm details to send full name ( ayewo ) nipa igbesi aiye ( dm ) 07047314225

👉MAWO aiye rẹ ran ,made isoro re Mara ooo,masu , koba le sun

Message me WhatsApp or call me
07047314225
👇 Awọn iṣẹ yi wale ni tita ooo 👇
07047314225

21/02/2026

ASEJE AGBOJO ASIRI BIBO

ASINA ATUDE  TABI ÉNIYAN  KAN TI OWANINU IDÉ AYÉ KAN ÉTARÁSASA LOBAMIN GBIYANJU ASIRIYI OOO  TI ÉSI MAMON WIPE TI O CONF...
21/02/2026

ASINA ATUDE TABI ÉNIYAN KAN TI OWANINU IDÉ AYÉ KAN ÉTARÁSASA LOBAMIN GBIYANJU ASIRIYI OOO TI ÉSI MAMON WIPE
TI O CONFIRM TRESTED AND CONFIRM OOO

MIORAYE ASODUN RARA

Eku asin 3.egbo tude topo.epo obo die pelu odidi atare kan a o jo po
LILORE 🦻 🦻 🦻

ti a bafe lo a o te ni ifa osa eleye.

PELU POEMS RÈ OOO

odere ori iroko.eiye aiye tike kaa kaa kaa.sebi eyin ni e ran eku asin ni ise.e sope ekukeku ko gbodo dena de eku asin.e sope eku toba dena de eku asin jinnijinni a se won.eniba fe dena ore aye mi.ki jinnijinni o se won o.tude wa tude ara emi - omo- ki o wa sina owo nlanla fun mi o.a o fi inkan gbona lo

Anfani siwafun éyiti ékobalesé iséyiyi fun arayin aleranyin lowo lori é call my number or msg me on Whatsapp 07047314225

Follow my page lati lejé awon anfani isémiran

Majẹmu rẹ ṣe adua funmi wipe mionifi OJUSUKUN òmò ati éyin na oooo

👉Fún ibẹrẹ Abi ọna abayọ lórí èyíkéyìí ogun TODOJU ko ooo
07047314225

👂Gbogbo aiye lowa tatise ( ayẹwo ) lati 12:00 t**i di 4:00pm details to send full name ( ayewo ) nipa igbesi aiye ( dm ) 07047314225

👉MAWO aiye rẹ ran ,made isoro re Mara ooo,masu , koba le sun

Message me WhatsApp or call me
07047314225
👇 Awọn iṣẹ yi wale ni tita ooo 👇
07047314225

20/02/2026

ATUDE TO CONFIRMED TRESTED AND CONFIRM 👍

ASINA ATUDE         MIORAYE ASODUN RARA Ewe ewuro ojo, epo obo, eru alamo ao gun papo oronro malu lama fi po ose yi omin...
20/02/2026

ASINA ATUDE

MIORAYE ASODUN RARA

Ewe ewuro ojo, epo obo, eru alamo ao gun papo oronro malu lama fi po ose yi omin kogbodo kan ao ko sinu roba fun fun ao wa so ori niwan ba si ao gbe sinu orun toba yo ao tun po papo ma ose yi taba tipo tan idire ko gbodo kanle mon oo amon siwaju ki étodawole ékoko bami share réna tori kini kankan ko tori anfani awon élomiran nani kiwon lebaje anfani isénani ooo
Lilore 🦻 🦻 🦻
ao ma fiwe ni ojo merin larin ose sunday monday tuesday thusday ti aba lo ose yi yato si awan ojo wonyi koni sise mon, taba si fe se ose yi arin ojo mererin yi lalese tabase yato si ojo mererin yi koni sise odaju

Anfani siwafun éyiti ékobalesé iséyiyi fun arayin aleranyin lowo lori é call my number or msg me on Whatsapp 07047314225

Follow my page lati lejé awon anfani isémiran

Majẹmu rẹ ṣe adua funmi wipe mionifi OJUSUKUN òmò ati éyin na oooo

👉Fún ibẹrẹ Abi ọna abayọ lórí èyíkéyìí ogun TODOJU ko ooo
07047314225

👂Gbogbo aiye lowa tatise ( ayẹwo ) lati 12:00 t**i di 4:00pm details to send full name ( ayewo ) nipa igbesi aiye ( dm ) 07047314225

👉MAWO aiye rẹ ran ,made isoro re Mara ooo,masu , koba le sun

Message me WhatsApp or call me
07047314225
👇 Awọn iṣẹ yi wale ni tita ooo 👇
07047314225

20/02/2026

ASÉJÉ ASIRI BIBO TI KONAYINJU 1.500 LO

ASIRI TI OTA FI NJADE LAYE /TI TUN SISÉ  ASINA NLA               MIORAYE ASODUN RARA Ao lo ra opolo ijokun nla kan, eepo...
20/02/2026

ASIRI TI OTA FI NJADE LAYE /TI TUN SISÉ ASINA NLA
MIORAYE ASODUN RARA

Ao lo ra opolo ijokun nla kan, eepo obo, igo epo pupa kan...ikoko tuntun..
SISERE 👇 👇 👇
Ao fi owo mu opolo yen. Ao se adura si leti otun. Ao sepe iku fun awon ota wa ni eti re keji...ao wa fi si inu ibi kan...Ao da epo pupa yen sinu ikoko tuntun na...ao wa gbe kana...ao je ki epo yen o gba daada hmmm mafi ijoti mowa ayé pelu ijoti mi oti mon igbati maku bi òta éniyan bagbé 100 otidi dandan fun won ésin bayini won ma séku tomon tomon ...ao wa ju eepo ebo sinu re...ao tun ni suuru ki o fi din daada...ti o ba se die ti ao gbo dindin eepo obo yen mo. ao wa ju opolo yen si nii aaye. yio si ku lekaana...ao wa ni suuru ki opolo yen o fi din daada...Ti o ba ti gbe daada...ao wa so ikoko yen. Kale lori ina...ao fi nkan yo opolo to ti din gbe sori olo ati epo obo yen...ao wa gun won papo mo ose dudu...epo ti a fi din yen ni ao fi po ose yi amon siwaju ki étodawole ékoko bami share réna tori kini kankan ko tori anfani awon élomiran nani kiwon lebaje anfani isénani ao wa ko ose na sinu ike funfun olomori kan...Ao ni suuru ki epo toku ninu ikoko yen o fi tutu daada..to ba ti tutu, ao wa da sinu ike kan.
Lilore 🦻 🦻 🦻
Ao ma fi ose yen we ni ale ati aaro...ti a ba ti we ose yi tan..ao fi epo ti a ro sinu ike yen fi ra idodo wa..opariGbogbo ota ti o ba ndi ire ayo wa lowo ni yio ku koto di ojo meje!!!...e danwo ni kiakia,odaju oooo gidi ni ooo

Anfani siwafun éyiti ékobalesé iséyiyi fun arayin aleranyin lowo lori é call my number or msg me on Whatsapp 07047314225

Follow my page lati lejé awon anfani isémiran

Majẹmu rẹ ṣe adua funmi wipe mionifi OJUSUKUN òmò ati éyin na oooo

👉Fún ibẹrẹ Abi ọna abayọ lórí èyíkéyìí ogun TODOJU ko ooo
07047314225

👂Gbogbo aiye lowa tatise ( ayẹwo ) lati 12:00 t**i di 4:00pm details to send full name ( ayewo ) nipa igbesi aiye ( dm ) 07047314225

👉MAWO aiye rẹ ran ,made isoro re Mara ooo,masu , koba le sun

Message me WhatsApp or call me
07047314225
👇 Awọn iṣẹ yi wale ni tita ooo 👇
07047314225

KI AWON AGBA LE TUN WAA SILEGBOGBO ÉYIN ÉNIYAN MI TOJASI WIPE GBOGBO ISÉNI ÉYIN TIFÉ SETAN NI ILÉ AYÉYIN AMON SIBÉ SIBÉ ...
19/02/2026

KI AWON AGBA LE TUN WAA SILE

GBOGBO ÉYIN ÉNIYAN MI TOJASI WIPE GBOGBO ISÉNI ÉYIN TIFÉ SETAN NI ILÉ AYÉYIN AMON SIBÉ SIBÉ KAKA KORO LARA ÒMÒ IYA AJÉ SISÉ NI OLÉSI HMMM ÉTARÁSASA LOBAMIN GBIYANJU ASIRIYI OOO PELU OGO T**I ÒLÒHUN ÒBA ÒRÒ AYÉYIN ANI OJUTU OOO AMON IWOTI OBAJASI WIPE KOSI IRU ÒSÉNA TI ÉKOTI WÉ TAN SIBÉ NA KOSI IYATO RARA OOO MALAGUN GINA BI ÉRU BAKAN OKÉ TI OSITUN KAN ILÉ OTUN NIBI AGBÉSI OOO CALL MY NUMBER OR MSG ME ON WHATSAPP 07047314225

ISÉNANI 👇 👇 👇 OO

Ewe lapa pupa die, egbo lapa funfun die, epo obo die, ata ijosi mesan fun okunrin meje fun obinrin, ewe afeloru die omundo re ni o. Ao gun mo ose iwe ojo meta, bi a baa fe we, ao fi epo pupa paa gbogbo ara dele. Ale ni ao we ose naa fun ojo meta,amon siwaju ki étodawole ékoko bami share réna tori kini kankan ko tori anfani awon élomiran nani kiwon lebaje anfani isénani ooo lehin ojo keta, ki obinrin se sara abo adie, ki okunrin se sara ako adie, eni naa ko gbodo je ni ibe... Akiyesi Pataki : ise ituwo aiye yii.... ao gbodo se fun ara waa, won gbodo se fun waa ni.... bi won baa ti se tan inu apadi ni ao gbesi, eniti o bawa se ose yii ko gbodo gbele wa lowo, hummm edakun e gbomi ye daadaa, ao ni si ise lo ooo, ti won baa ti bawa gun tan ti won ti ko sinu apadi, ao tewo gbaa sugbon kaka ki eni naa gbe fun waa yio ju sile ni ti apadi naa baa ti bosile ao waa fi owo ara waa gbe

Anfani siwafun éyiti ékobalesé iséyiyi fun arayin aleranyin lowo lori é call my number or msg me on Whatsapp 07047314225

Follow my page lati lejé awon anfani isémiran

Majẹmu rẹ ṣe adua funmi wipe mionifi OJUSUKUN òmò ati éyin na oooo

👉Fún ibẹrẹ Abi ọna abayọ lórí èyíkéyìí ogun TODOJU ko ooo
07047314225

👂Gbogbo aiye lowa tatise ( ayẹwo ) lati 12:00 t**i di 4:00pm details to send full name ( ayewo ) nipa igbesi aiye ( dm ) 07047314225

👉MAWO aiye rẹ ran ,made isoro re Mara ooo,masu , koba le sun

Message me WhatsApp or call me
07047314225
👇 Awọn iṣẹ yi wale ni tita ooo 👇
07047314225

Address

ÒTÉ AREA
Ogbomoso

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when YARA ASIRI AYÉ posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram