Asiri ewe ati agbara egbo

Asiri ewe ati agbara egbo fun orísirísi iwosan

14/06/2023

Moki gbogbo wa ku ifarada asiko yio, eledumare koni kodi aimonse sí ẹni kọkan wao, ti aba ni ki gbogbo wa wo bi inkan seri lasiko yi ao ri wipe ọpọlọpọ sise ṣiṣe loti n'dabi ole leyi ti osi je ki opo okunrin di alai mo se lodo obinrin míràn, eyi l'omumi lati fẹ yọnda asiri bibo yi, ki oni kaluku wa gbiyanju rẹ wò, ki afi wa bibo asiri kiakia,
Àṣírí náà niyi,
Ao wa eso ta gììrì odidi kan, ti oni àjé lara dáadáa, ao pa ni panṣa, ao ko idoti inu re danu, ao wa ekiri ẹran maalu kan, tí koiti wo omi, koni sise fun ọ ti o bá share rẹ kio sí like page yii, tori anfani elo miran,ao fi ekiri ẹran maalu náà sí inú tàgíìrì náà ao dé pa, ao gbé tàgíìrì náà lé orí iná fún bí ọgbọn isẹju,30 minute, ao wa je ki ọ tutu niwon ba, ao wa yọ ekiri ẹran yen ninu tàgíìrì náà,ao ju senu ni ẹẹkan náà, ao je. Yíó bawa lara mu oo, sope àṣírí témi koni tu ooo.

Copied                                                                                  DO NOT DIE IN SILENCE, DO IT YOU...
13/06/2023

Copied

DO NOT DIE IN SILENCE,
DO IT YOURSELF.

1. ENGLISH: TYPHOID FEVER (1)
Take Alabukun with lime water, squeeze ugu vegetable into a glass cup with two local eggs, half tin milk and two spoons of natural honey mix together and drink it. Three times a day after meal.

YORUBA: IBA JEDOJEDO (1)
E lo Alabukun pelu omi osan wewe, egbo efo igu sinu cup kan,eyin adie ibile meji, idaji agolo miliki ati sibi oyin igan meji, e po papapo ki e si gbemu. Emeta loojumo leyin ounje.

2. ENGLISH: TYPHOID FEVER (2)
Ten lime oranges (H20) mixed with garlic and three teaspoons of original honey should be used morning & night after meal.

YORUBA: IBA JEDOJEDO (2)
E fun osan wewe mewa,lo ayu(garlic) si, pelu sibi oyin igan meta. Eloo leemeji lojumo aaro ati ale.

3. ENGLISH: TYPHOID FEVER (3)
Get unripe pawpaw, unripe pineapple, ginger, lime orange, sugarcane and Lipton tea 2sachet.Cut everything into Pieces and boil them with fermented corn water(omidun) for one hour+. Take one glass cup 3 times daily for one week with original honey mix together.

YORUBA: IBA JEDOJEDO (3)
E wa ipepe ati ope oyinbo dudu, atale, osan wewe, ireke ati lipton tea meji. E ge gbogbo awon eso wonyi, ki e si fi omidun se e fun wakati kan ati die. E ma mu ife kan ni eemata ni ojojumo pelu oyin igan die ninu e fun ose kan.

4. ENGLISH: EZEMA/RING WORM
Mix some native soap with grounded potash, add lime orange to it and apply the mixture on the spot after bathe.

YORUBA: IFO/EELA
E mu ose dudu ibile, koun ti a nfi nsebe ati omi osan wewe, e po gbogbo e papo ki e fi ma pa oju e.

5. ENGLISH: HYNEA
Get some leavesof casia alata, boil with water and drink one glass cup daily.

YORUBA: IPAKE
E mu ewe panseke ki e se pelu omi ti o mo ki e fi oyin igan die si. E ma mu ife kan ni ojojumo.

6. ENGLISH: INTERNAL HEAT
Get some quantity of dry pawpaw and cashew leaves. Boil with water and drink 1 cup 2 times daily.

YORUBA: ORU INU
Ewe ipepe ati ewe kasu ti o ti gbe daada. E se ki e ma mu ife(cup) ni emeji ni ojujumo.

7. ENGLISH: NATURAL FAMILY PLANING
Get some root of cashew tree, boil and add original honey to it. Take one cup per day after monthly period for one week before making love.

8. ENGLISH: JAUNDICE PAIN
Get the water of unripe pineapple, three lime oranges, and three ijagaun orange, mix them together. Four spoons 3 times a day after meal.

YORUBA: AWOKA ARA
Fun omi ope oyinbo ti kopon, pelu osan wewe meta, osan ijagaun meta papo, sibi merin, eemeta lijumo leyin ounje.

9. ENGLISH: A**S PULLING OUT (1)
Tetracycline (6) mixes with original honey 2 spoons. Rub the a**s with the solution when it pulls out.

YORUBA: IDI YIYO (1)
E po tetracycline (6) pelu sibi oyin igan meji.
E maa fira idi na ti o ba tiyo.

10. ENGLISH: ULCER (1)
Use three spoons of original honey with pap early in the morning before meal for 6 days.

YORUBA: OGBE INU (1)
A o fi sibi oyin igan meta fo eko mu laaro ki a to jeun fun ojo mefa.

11. ENGLISH: ULCER (2)
Squeeze either pineapple or pawpaw seed to produce water and filter it. Mix the solution with tin milk and drink it for seven days.

YORUBA: OGBE INU (2)
A o gbo pineapple tabi eso ibepe a o se. A o po agolo milk kan mo. A o si mu fun ojo meje.

12. ENGLISH: ULCER (3)
Get 8 unripe plantains, peel them and cut them into pieces and pound them to paste. Pack everything into a container (1 five litters gallon), fill the gallon with drinkable water add little honey. Allow to ferment for 3-5days and take one cup 2 times a day.

YORUBA: OGBE INU (3)
E mu ogede agbagba dudu mejo, e bo lara ki si rin dada ni tutu. leyin eyi, e ko sinu galonu kan ti e ti pese sile, e ro omi mimu sinu e pelu oyin igan die e file fun ojo meta ki o toro dada. E ma mu ife(cup) meji leemeji lojumo.

13. ENGLISH: TOO MUCH FAT (OBESITY)
Peel the back of maize, lime orange and cook them with water. One tumbler 3 times daily.

YORUBA: ARA SISAN JU
Eepo eyin agbado, osan wewe, a o se pelu omi lasan. 1 tumbler emeta lojumo.

14. ENGLISH: SLEEPLESS NIGHT(1)
Undiluted honey, aloe Vera juice mixed together, take two or 3 spoons every day.

YORUBA: AIRI ORUN SUN DAADA (1)
Ogidi oyin ilarin coke, oje ewe eti erin (aloe vera), a o da papo, sibi metameta lojojumo.


15. ENGLISH: SLEEPLESS NIGHT (2)
Add(2) 3 spoons of honey into glass cup of milk(low in cholesterol).Take all as soon as you are ready to go to bed.

YORUBA: AIRI ORUN SUN DAADA (2)
E da sibi oyin igan gidi meta sinu ife miliki kan, ki esi mu ni ale ti e ba ti fe sun.

16. ENGLISH: WEAKNESS OF THE BODY
Cut aloe Vera into cup, put water for 5 minutes and drink the liquid.

17. ENGLISH: THROAT PROBLEM
A handful of Abeere seed, grind it well and mix it with honey (half coke bottle).One spoon every hour.

YORUBA: BELUBELU
A o lo eso abeere ekunwo kan kunna, a o fi sinu oyin igan idaji igo coke. Sibi kan wakati.
Follow Page yin fún akotun anfani miran
Share resi awọn group kakiri fún anfani ẹlòmíràn,ao ni se àìsàn o, bẹẹni eledumare koni je ki àìsàn se eni kọọkan wa

13/06/2023

(1) Efo GBURE ati EGBO RE wa fun ; OWO TO NGBON, AHAN to nlo. (STROKE) A o tu GBURE pelu egbo re a o foo daradara a o se fun iseju marundinlogun (15 Minutes)
Dosage: A glass cup 2 Times daily.

(2) CANCER /PROSTRATE, THE KILLER DISEASE
OSAN WEWE MERIN; (LIME) a o ge si meji a o se daradara. Dosage a o ma mun ni gbigbona ti yio maa jo wa ninu ati lenu gan. 2-3 times daily. Please very effective.

(3) LOW / HIGH B/ P; EWE PEAR A o se fun 20- 25 Minutes.
Dosage ; a glass cup two times daily Please after THREE days go and check you B/P

(4) DIABETES IS A DEADLY DIOCESES"

Powder OSAN AGBALUMO / ATI POWDER ABEERE, A o wa omi AGBON (COCONUT WATER) ONE BIG BOTTLE OF TABLE WATER A O BU SIBI MEJI MEJI (TWO TWO SPOONS) si nu re. To ferment for 3 days.
Dosage ; a short (smaĺl cup) drink twice daily until you finish the bottle.

(5) Oyi OJU, OYI ORI ATI OYI INU. A O WA EWE (IYEYE) A O JA A.
A O gboo daradara, A o fi IYO DIE si. Small SAULT.
Dosage; a glass cup 3 times daily

(6) AGBO JEDI-JEDI TO MU NA DOKO.
EEPO OKURU-KURU, PELU ALUBOSA AYU ATI KAFURA. A O FO NU A O KO SINU KEG TO NI IDERI FUN OJO MEJI (24) HRS
Dosage a glass cup two times daily. Kii ya enia ni igbe rara...

7. OGUN ROPAROSE - STROKE TODAJU

Owo iwaju Aja ati ese eyin Aja mejeji. odindin Atare Aja kan. E jo gbogbo re papo, E o sin gbere yika orun Owo ati Ese yin mejeji ati Orikiriki gbogbo Ara. Ki e wa fi Ebu naa kun oju gbere naa daadaa.

8.OGUN ARA TITA Ati ESE TITA

Osan Jagain Mewa (10), Osan Oronbo mewa (10), e o ge awon Osan naa si mejimeji. Ewe Ireke tutu. E o fi Omindun se awon Eroja naa, ko jina daadaa. Ki e maa mu Cup meji lojumo.

9.OGUN JEDANJEDAN - CANCER LIVER

Eso Taba pupo die, Odindin Oga gbigbe kan. Eyin Ibile mefa (6), Odindin Atare kan. e jo gbogbo re papo. ki e lo, ko kuna daadaa. ki e wa da EBU naa si ADIEYAN. Ki e maa mu Sibi kan laaro ati Sibi kan ni Ale.

10. 0GUN WARAPA TODAJU - EPILEPSY

Omonle Aiye kan, Epo-Obo die, Odindin Atare Aja kan, e jo gbogbo re papo. ki e da Ebu naa sinu Oti Ogogoro tabi Shinapp. Ki e maa mu Cup kekere kan laaro ati lale (Twice in a Day).

11. OGUN GIRI AGBALAGBA ATI OMODE - CONVULSION

Eku Asin gbigbe kan, Iseta, Ewe Taba tutu, Ewe Kataba gbigbe. Ewe Taba Oyinbo, Alubosa Elewe, Ewe Taba Juku, e re gbogbe Eroja naa sinu Oti Ogogoro tabi Shinapp. ki e maa mu Cup kekere meji lojumo. (Twice in a Day.) tabi ki e lo gbogbo Eroja yen mo Ose dudu ki e maa fi Ose naa we laarolaaro.

12. OGUN ATOSI - GONORRHEA

Epa Ikun, Bara, E o be Bara naa. e o yo gbogbo koro inu re danu. E o ge kekeke sinu Ike funfun. E o fi Oti Ogogoro re fun (4 days). E o ma mu Cup kekere meji lojumo. (Twice in a A day).

13. EDA OBINRIN - VIRGINAL DISCHARGE

Osan wewe mejila (12), e ge si kekeke, Atale tutu, Alubosa Ayu tutu, Ewe Efinrin pupo. E fi Omi se gbogbo Eroja naa, ko jina daadaa. ki e maa mu Cup meji lojumo, (Twice in a Day).

EDA OBINRIN - VIRGINAL DISCHARGE

Ewe Dasa gbigbe pupo. e lo, ko kuna daadaa. Ki Obinrin maa fi fo Eko mu laarolaaro. tabi ki e lo Ewe Dasa naa mo Ose dudu, ki Obinrin maa fi Ose naa fo Oju Ara re.

14. OGUN IKO - ASTHMA

Odindin Oga gbigbe kan, E lo ko kuna daadaa, Ki e da sinu Oyin Orijinal, ki e maa mu Sibi kookan lojumo (Once in a Day).

15. ATO TO SAN- LOW S***M COUNT

Oyin Sibi merin, Eyin Adie Agric merin, Pilk Milk kan, E o da gbogbo re papo sinu Cup, Ki e gbe gbogbo re mu lekan. Ki e maa mu ni emeji laarin Ose (Twice in a Week).
E jeki a share rẹ fún anfani ẹlòmíràn
Copied

13/06/2023

Akiyin kaabo sí ojú òpó asiri ewe ati agbara egbo, fún itusile ati ida nde omo niyan, ki eledumare kun igbiyanju enikookan wa lowo,esi je ki eni kọọkan wa ma gbiyanju lati ma share gbogbo anfani ti aba nba pade loju òpó yin, fún anfani ẹlòmíràn, Aajuwaa seo

Address

Akódá
Osun
100011

Telephone

+2348149567694

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Asiri ewe ati agbara egbo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram