Dr. Nohu herbal

  • Home
  • Dr. Nohu herbal

Dr. Nohu herbal specialist on prostate enlargement/UTI/STDs and spiritual problems

16/01/2026
16/01/2026

Man behind my story 👇

13/01/2026
Kinni Oruko ta n pe Ewe yi ni ile wa👇
12/01/2026

Kinni Oruko ta n pe Ewe yi ni ile wa👇

IWULO EWE ODUKU (POTATO LEAF)•Fun Iwosan Iseto (Prostate)•Akando (Whiklo)•Inu Rirun (Stomach ache)•Ara Riro (Body Pain)•...
10/01/2026

IWULO EWE ODUKU
(POTATO LEAF)
•Fun Iwosan Iseto (Prostate)
•Akando (Whiklo)
•Inu Rirun (Stomach ache)
•Ara Riro (Body Pain)
•Ogbe Inu (Ulcer)

Gbogbo Ohun ti Oluwa da, daradara ni, Olohun oba ko sadede seda Ewe Ati Egbo si Ori oke Yerupe, bi kiise fun Anfani Ati Lilo awa Eda.

Ewe yi nsise fun Oniruru Aisan Ati Awon Ipenija Miran Ninu ago Ara wa.

•Fun Aisan Iseto (Prostate)
Ki a ja Tutu Ewe yi, ki a gun papo mo Egbo iyalode Funfun, ki a wa re (soak) sinu Omi ti o bamo dada fun bi wakati Mejo (8hrs) ki a se (Filter) ki a ro sinu ike TI o ba Mo dada.

LILO RE
Ao ma mu ni Idaji Stainless cup kan ni Emeji lojumo
(Owuro Ati Ale).

•Fun Ara Riro (Body Pain)
Ki Eni na ki o Wa EWE yi Tutu, ki a gun Ninu odo (Malta) ki a wa fi omi re (soak) fun bi wakati Meji/meta, ki a Mafi Omi na we ti Abafe sun lale, ki a sima bu Iyo Isebe (Salt) sinu Omi na.

Pelu ogo olohun oba ti eniyan base bee fun bi Ose Meji, Eni na ko tun gburo ohun ti o nje Ara Riro mo Ninu Aago Ara re.

•Fun Akando (Whitlows)
Ki a ja Omudun Ewe yi, ki a gun pelu Omo atare iyekiye, ki a wa po papo mo Ori (Share butter), ki a wa san mo Oju re, ki a fi Akisa a*o di mo.

Pelu ogo olohun oba, Akando na malo laarin ojo Meji si meta.

Kiise Gbogbo IWULO EWE yi ni a le salaye re tan, Sugbon Ao tun ma tesiwaju ni ojomiran.

Gbogbo wa konifi Aisan Logba oo🙏

Iwo na bami share re fun Anfani Awon Elomiran.

Ire oooo!

Ise Asina (fortune Booster)â—ŹEwe iyalode funfun 16â—ŹEyin agric (agric egg)â—ŹOwo tuntun (new currency)â—ŹIkoko (local pot)Ao w...
08/01/2026

Ise Asina (fortune Booster)

â—ŹEwe iyalode funfun 16

â—ŹEyin agric (agric egg)

â—ŹOwo tuntun (new currency)

â—ŹIkoko (local pot)

Ao wa ewe lapalapa mejidilogun 16 pcs,
Ao fi mejo ewe lapalapa tele isasun yi leyin na ni ao ko eyin (egg) meta lelori, ewe lapalapa mejo yio kun ao ko lelori leyin na ni ao de pelu omo ideri isasun
Ao se jinna Larin iseju meta si marun
To ba ti jinna tan idi re kogbodo kanle mon, to ba ti tutu ao te owo tuntun na si ori table ao gbe isasun yi lelori ao wa se adura, leyin na ni abo eyin meteta yi, odi jije

Owo na ao mu losi inu oja toba tobi lati fi lora nkan to ba ti wu wa.

Iwo na bami share re fun iwulo awon Elomiran ki won o le je Anfani re

Fun ibere
08022633112

IKOSEMISEMI (ASTHMA)Ewe bomubomu la fi toju aisan iko semisemi (Asthma)Ao wa nkan meta ti akasile yi.* Ewe bomubomu (sod...
30/12/2025

IKOSEMISEMI (ASTHMA)

Ewe bomubomu la fi toju aisan iko semisemi (Asthma)

Ao wa nkan meta ti akasile yi.
* Ewe bomubomu (sodium apple),
* Iyere (Ashanti pepper)
* Iyo (salt) Ati oyin (honey)

Iwadi ijinle ni ilana ibile jeki amonpe ogun yi la fise itoju eyikeyi iko (cough) to ba da eniyan lamu, to je wipe to n ba lo ogun yi Larin ose kan si ikeji alafia tide

Ao lo ewe bomubomu yi ati iyere po, to ba ti kunna dada, ao da sinu epo pupa tabi oyin

Odi lila laro, osan ati Ale.
Larin ose kan si ikeji wa dupe lowo olohun

Fun ibere ati alaye 08022633112

゚viralfbreelsfypシ゚viral

IWULO EWE BOMUBOMU (HEALRTH BENEFITS SODIUM APPLE) Fun itoju aisan bi * Pajapaja owo ati ese (Pain and Niddles)* Egun Ri...
28/12/2025

IWULO EWE BOMUBOMU
(HEALRTH BENEFITS SODIUM APPLE)
Fun itoju aisan bi
* Pajapaja owo ati ese (Pain and Niddles)
* Egun Riro (Rheumatism)
* Atogbe (diabetes)
* Aikori orunsun (insomnia)
* Aisan ibalopo (Sti/STDs)
* Iko ati Otutu (cough and cold)
* Kokoro Ara (Skin infections)
* Iko Swmisemi (Asthma)

Ewe, Eso,egbo ati omi bomubomu lafi se itoju awon aisan ti akasile yi

Ninu iwadi ijinle ni ilana ibile je kamon wipe olohun kosa dede da ewe ati egbo si ile erupe bi kiise fun anfani lati fise iwosan ara.
Iwadi jeki oye wa wipe oni ru iru ero ara ewe bomubomu ama mu adiku ba Aisan bi Ara riro (pain), kokoro aifi ojuri (micro bacteria organisms) ati bebelo.
Bayi mofe se alaye ni ranpe lori awon ona ti alegba lati lo ewe yi pelu egbo re.
Opolopo loti lo onirurun ogun ibile ati ti oyinbo, sugbon kosi Iyato rara.
Ti oba lo ohun ti ko e, oda mi loju pe wa dupe lowo eledumare.

* PAJAPAJA OWO ATI ESE (PINS/NIDDLES) gbogbo eniyan to ba ni ipenija aisan yi kolo wa tutu ewe bomubomu kio ma dade atelese re mejeji ni ale (night) pelu awo bese (sucks) ko to sun lake, kose be fun ose meji abi meta gbako

Iwulo yi dara fun awon Arugbo wa.
Fun ibere 08022633112

16/12/2025

Take care of your body. It's the only place you have to live
13/12/2025

Take care of your body. It's the only place you have to live

IWULO EWE ABAMODA•IIfunpa Giga (High Blood Pressure)•Ito Suga (Diabetes)•Aikori Orun Sun (Insomnia)•Ogbe Inu (Ulcer)•Ori...
12/12/2025

IWULO EWE ABAMODA
•IIfunpa Giga (High Blood Pressure)
•Ito Suga (Diabetes)
•Aikori Orun Sun (Insomnia)
•Ogbe Inu (Ulcer)
•Ori Fifo Tulu (Constant Headache)

Ewe yi ni awon Eronja pupo ti o le mamu adinku ba irora ati awon ipenija miran.

BI AO SESE
Ao ja ewe yi ni tutu ao gun papo mo ata ile pupa (Tumeric) so sa ki o gbe dada, ao malo ni sibi imuko kan ni owuro ati Ale.

Fun ibere
08022633112

27/11/2024

Address

Ilorin

031

Telephone

+2348022633112

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Dr. Nohu herbal posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Dr. Nohu herbal:

  • Want your practice to be the top-listed Clinic?

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram