ASIRI NBE

ASIRI NBE EGBE ASIRI NBE...
Wa fun eko nipa ogun ibile,pelu nilo ewe ati egbo,pelu eran ko fun nilo omo eniyan

25/10/2021
ETO FUN ENITI O BA NLEPA DUKIA.aro awọn ti wọn ba lepa dukia ki o se hontu Onibeji tíó wa loke yi,kio oni tohun lọra a*o...
21/01/2021

ETO FUN ENITI O BA NLEPA DUKIA.

aro awọn ti wọn ba lepa dukia ki o se hontu Onibeji tíó wa loke yi,kio oni tohun lọra a*o fúnfún sori ibusure(bed) ni ojo Monday,iye k'iye ti won bape ni kio ra oooo,ko gbodo na rárá,ati eyi tia fi bora na ati eyi tia tẹ sori ibusun re pelu, da ọjọ Sunday,toba tile hàn hontu oni beji yi,ko fi abela alawọ ewe jọ ni ojo Sunday,ni agọ kan oru,kio sì mafi omi okun gbe mu fún ọjọ méje,ao wa pa agbo funfun kan ọkan agbo yi nikan lamaje,ao fi èyí toko se sara fun awọn eyan,ao má fi a*o funfun bora sun ati eyi tio wa lori ibusun,

akiyesi..bio bani eni tio sope kíá ba ohun gba owo dani kíá Mope ajemonu wa ni,

NOTE..agbodo ma se aanu fún àwọn alani,ohun ni amu inu awọn malaika yẹ dun lati pada wa gbé ọwọ fún wa,tabi kíá ràn isé Oluwa lọwọ ni ile ijosi...

tia ba fi ọwọ yi se aanu walahi ìgbésí aiye oni tohun ada radarada ni,koju belo

Lati owo oludasile ẹgbẹ
09036646204
09015903874

Dupe lowo eledumare oba akoda asèdá,kio ba le jẹ fún ooo

21/01/2021

OGUN FAMILY PLANNING.
ODUN KAN ATI OSU MEJI LOMA LO LARA:
ESO IYALODE FUNFUN AO yo funfun inu e kan ama lo bi tablet ,to ba di ojo keta ti ati lo
ama mu agbo jejdijedi OMA bere ise ni ojo keta ko ni wahala kankan be niko si
(repercussion) odunkan leyi fin sise
nigbati obinrin ba nse nkan osu,ao fi owu soju arawa moju ojo keji ao jeki owu yipo
die,ao wa yo laro ojo keji,ao wa ja ibi ti eje yen ba soak dada ninu owu yen,ao so iyi toku
nu,ao wafi iyiti a ja yen sinu efe owu miran,ao fi oko atare kan si legbe,ao di niko bere
pelu owu dd ati ff,ao wa ju sinu igo cream to de dada gan,ao wabu adin si ninu,loba pari
ooo,hmmmmmmmm bi ogo ti nje ti Olorun onitoun kole loyun.
ERO RE>ao shi igo adin yi,ao danu,ao yo ogun yi,ao tun ka sototo,ao ko danu,lehin eyi ti
a ba sunmo okunrin hmmmm,a nbo waje rice

Lati owo oludasile ẹgbẹ..

Number...09036646204...09015903874

Dupe lọwọ ọlọrun kio ba le je fún ooo

21/01/2021

OGUN TI OYUN NBA BAJE LARA OBINRIN TABI EDA EWE IMI ESU A O GBO NINU OGIDI EMU A O YO DADA A O DA
SINU IGO KAN OBINRIN NA YO MA MU DIEDIE ( IKILO) EJO DIE DIE NI O OBINRIN NA LE MA YA IGBE ORISIRISI
OGUN YI YO FO GBOGBO IDOTI INU RE.....

Lati owo oludasile ẹgbẹ...
Number...09036646204...09015903874

Dupe lowo eledumare kio ba le je fún ooo

18/01/2021

ASIRI IFERAN ONI KOKORO
Ewe amunimuye,ewe sawerepepe,iru,ati iyere,aolopo fise eja aro kan,aose tiyojina dada
pelu epo ati iyo,aoso agadagodo kan sinu obe yi aose mo,tobajinaa aoso idire kogbodo
kanle,toba tutu,aogba aseje yi dani ni ihoho omoluabi,-lamorin omo lamorin,emi lamorin
omo lamorin nimonpeo,ibikibi ti obawa kowa jemini hoo,sawerepepe kolope lol tiise
ayami wafunmi loni,emi lol tiise okore nimonpe o,amunimuye walo bami mu iye lol tiise
ayami loni,iyere walo bami mu iye lol wasi odomi loni,iyo loni ki lol mayo momi kakiri
lojojumo,aro loni ki lol maro momi kakiri lati oni lo,oroti moba ba*o nikogbo,tori wipe
oro ti kokoro baba agadagodo so niigbo,obe ti emi lol fejeyi kogbodo duro si inumi,inu
lol nikolo sokale si kiakia timoba tije tan,aoso bi asefe kori si aowaje obe yi,leyin na ao
wa mu agadagodo yi aotipa,odi inu odo nla

Lati owo oludasile ẹgbẹ....09036646204...09015903874

Dupe lowo eledumare oba akoda asèdá,kio baleje fún ooo

15/01/2021

ETUTU TI AFI UN TORO ORE LOWO AWON AGBA,
Eye onbe meta odidi atare kan ao Jo papo ao lokunna ao ro sinu ado kekere kan ao ma ra akara
elepo meta meta ni ojojumo fun ojo meje ao mafi ebu si ao ma gbe si ita gbangba ao ma toro
inkan eyo kan pere ao ni fi epo pupa sio,o daju dada ti won bati gba fun ojo mejeje inkan na yo
ribe odaju

Lati owo Dr Eriloluwa..no..09036646204.....09015903874

Dupe lowo eledumare kio baleje fún ooo

15/01/2021

WEGUN WEPE TO GBONA
Elo wa egbo tude tutu ati ewe re,egbo iyalode funfun die,pupa die,ewe iyalode funfun
ati pupa die die,epo oboh die ewe ajeobale die tobaje pe obirin lafe se ise yii fun ata
wewe adaiyeba meje tobaje okurin ni ata mesan eo pa awon egbo yen peepepe ao yo
igi inu re danu ao gun epo arawon po mo awon ewe yen pelu ata ao fi ewe ejirin wewe
se kainkain fun,wiwe lodo to nsan fun ojo meta lerawon pelu fifi epo pupa pa ara.

Lati owo oludasile ẹgbẹ Dr ERILOLUWA...no...09036646204...09015903874

Dupe lowo eledumare kio leje fún ooo

15/01/2021

1. Aseje agoojo
ao haa Ara egbo tude,ao loo mo Ata ijosi, ao fise pomo mesan je laaro. Lepo niyo ni oo

2. Aseje agboojo
Ewe etiponla ao loopo mo Ata ijosi ao fise pomo mesan je lepo niyo

3. Turare agboojo
Egbo Etiponla ao gun ao pomo Ori die ao ma fin, ao ri wipe a gba eefin re si ara oo. Odaju

4. Ose itaja gidi
Eru Alamo pupo, epo obo topoo, a o gun kunaa mo ose ao waa fi eje malu poo po,ao wa ko sinu igba olomori kan . Ao ma we lararo.
Note..ao po osun ati efun papo pelu hot, ao fi te ejiogbe si ara igba yen. Odaju

5. Osole gidi
Ejo oka aaye kan ti a ti pa lapa sara,ao fi #1000 we eran Ijimere basi kan, ao fi igi kibo lenu yoo wole kanle,ao gbe sinu ikoko, ao pa eiyele meji lee Lori, ao la aiya awon eyele naa, ao daa dee ejo yen mole pelu atare kan, ao jopo, ao rosinu igo funfun. Ao ma fi hot loo. Odaju

6. Adodun
a o ki eso werepe bo idi abo adie kan ao fisile fun gbadie koma japoro kiri, lehin bi iseju mewa, ao mu ao ge idi re mo eso yerepe yen jijo pelu odidi atare kan , ewe amunimuye, ewe adun, ao fi singbere ao tun po mo ori ao mafi paa Abe. Odaju daada, ti okunrin ba kosi panpe yi lara obinrin, o ti di ATM niyen oo. Okunrin naa lee loo.

7. Iwe odo ti a fi nri owo.
Egbo Yanri ao gun kunna pelu epo Obo ao pomo ose, ao lo fi we ni odo tonsan. Ao koko fi epo pupa para ki a to wee oo.

8. ASHINA,AJEGUN ati ASETA .
Edun Ara ao lo kunna pelu ewe ojiji ati Eja ojiji aiye kan ao po mo ose,ao tun fi Eja ojiji aiye kan tele Ike funfun tabi igba,ao ko ose yi lee lori fun ojo meje, ao ma fi we lararo leyin ojo keje yen. Odaju.

Kole jẹ fún ọooo,se adura fún ẹgbẹ yi pe ẹgbẹ yi oni tun....

Lati owo oludasile ẹgbẹ Dr ERIOLUWA....no...09036646204....09015903874

14/01/2021

Moki gbogbo ọmọ ẹgbẹ́,pe aku odun akuye dun,ọtọ ojo meta,

IMULE AWỌN AGBA TODAJU.

Ào wa ifun inu òkété Titun kan,ati ẹyẹ onbe kàn,ao wa gun mejeji mó ọṣe dúdú,ao wa ko sinu epo obo tio fe dada,ao wa fi ikode gún lori,ao gbe pamo fún ojó méta leyin ojo keta,ao ma fiwe lalale kio to sun,ao gbodo jade mo ni ojo na,odaju.

Lati owo oludasile ẹgbẹ..
Fún ibere ..09036646204,09015903874

Koleje fún ọoo,sope malu aluyo,

24/11/2020

Asiri nbe lodo awon agba

12/11/2020

IMULE AWON AGBA TOSINA OWO TARA
ESO LAPA TIKOTIPON TIKOTI DI YELLOW LORI IGI RE AOLA AOYO KORO INU RE META HUN AOLO IKOKAN MO OSE IWE OKO KAN TI YIOFIPE META TABAFE WE AOFI ADI EYAN PARA WE AKOKO EPO PARA WE EKEJI OYIN PARA WE IKETA PELU ADUA OWO NLANLA IRE O

Address

Ado-Ekiti

Telephone

+2349036646204

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ASIRI NBE posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to ASIRI NBE:

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram

Category