Ejiogbe Eyinju Ifa

Ejiogbe Eyinju Ifa OLUWO EJIOGBE SPIRITUAL HEALING and WEALTHY CENTER

04/11/2025

Ise Amunimuye
Ise Asegbe
Agbara OMO ALAJE

Happy Sunday everyone 😍😍🙏🙏🙏This week you shall receive a good news
02/11/2025

Happy Sunday everyone 😍😍🙏🙏🙏
This week you shall receive a good news

01/11/2025

Oshole Aseyori
Agbara OMO ALAJE

Happy New Month This month you shall be celebrated 🙏🙏🙏
01/11/2025

Happy New Month
This month you shall be celebrated 🙏🙏🙏

31/10/2025

Awenu Todaju
Agbara OMO ALAJE

ASEJE ASINA ELOBAMI WA  PONMO IJEBU ..EWE SAWEREPEPE NIWONBA ..ITANNA TANNAGBOWO 16 ATA IJOSI 16 EWE OLA DIE NI O EJO MO...
31/10/2025

ASEJE ASINA
ELOBAMI WA PONMO IJEBU ..EWE SAWEREPEPE NIWONBA ..ITANNA TANNAGBOWO 16 ATA IJOSI 16 EWE OLA DIE NI O EJO MOBE GBOGBO ILE PATAPATA EWE OLA YII NIWON BANI O AO WALO GBOGBO EROJA YI PAPO AO GE PONMO WA SI 16 AO FA AWON EROJA TI ALO YII SINU ISASUN ASEJE WA AOWA SAN PONMO YII DASI AOGBE KA ORI INA AOFI EPO DIE IYO DIE SI TOBA JI NAA TAN KA*O SORI OSUNKA A*O FUNFUN AOWA SE ADURA SI

TI ABA NJE ASEJE YII LOWO ESE WA KOGBIDO KANLE O AKOSI NI JE IKAN TAN LENU TI AOFI MA JE IMI T**I TIYOFITAN

MAJEMU ISE YII NI KO SHARE RE SELOMI KOLEBAJE ANFANI FUN AWON NAA

KOFI COMMENT RE SOWIPE ADURA MI TIGBA ....ADURA GBOGBO WA NI YO GBA LASE EDUMARE 🙏🙏🙏

EYONU ASINA YI NAA GBIYANJU NIWON BI AGBARA RẸ MONEwe iyalode funfun oojọ Ewe iyalode pupa  oojọ Ewe akoko oojọ Gigun mọ...
29/10/2025

EYONU ASINA YI NAA GBIYANJU NIWON BI AGBARA RẸ MON

Ewe iyalode funfun oojọ
Ewe iyalode pupa oojọ
Ewe akoko oojọ
Gigun mọ ose agayin tabi ose Ghana
Aofi omi àgbọn po papọ
Eo fi akọ epo obọ̀ diẹ tele inu ike funfun
Aoko ọsẹ naa le lori
Ao ma fiwẹ́ ni owurọ kutu
Èdùmàrè yio jeki obayin lara mu bii tero iṣaaju

RIDAJU PE O SHARE RE
Fi adura rẹ ranṣẹ

29/10/2025
29/10/2025
29/10/2025
29/10/2025

Atude Owo aye
Asina
Eyonu Agba Agbara OMO ALAJE

Address

Ijoka
Akure

Telephone

+2347047662115

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ejiogbe Eyinju Ifa posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram