26/11/2025
ASEJẸ AWURE TODAJU BIKU
Ọga ibilẹ gbigbẹ kan 1
Ewe sawerepepe tutu diẹ
Iru diẹ
Ata ijọsin diẹ
Ẹyin ororo Mẹta 3
Owo paper #200 Kan
Ori diẹ
SISE RẸ :
Ao lọ Oga ati iru ati ewe sawerepepe ati ata ati owo paper LỌTỌTỌ,
ao da sinu abo kan, ao fọ awọn ẹyin si, ao po papọ, ao gbe koko ka ori Ina ti oba ti gbona daaadaaa ao ju ori yi si ti yọ, ao da gbogbo eroja ti apo papo sinu abo yi sinu ape ninu ori yii, ao fi ori yii din je ni aseje, ti oba jina,ao so sori Osuka ao se adua iwure, si ao ko jẹ.
ODAJU BIIKU
ONDE ỌWỌ / IBỌN AJEDIN
Ibẹpẹ dudu kan 1
Akọ alangba kan 1
Odidi atare meje 7
Ao ge ibepe na lori ni pansa,
Ao wa rọra kaa alangba na sinu rẹ
Ao wa fi odidi atare méje sinu rẹ
Ao de pada , Ao wa jo ao lọ kuna daadaa
Ao da ẹtu rẹ sinu owu otutu
Ao fi owu dudu ati funfun dii
Ao wa ran ni awo dudu ni onde sidi
Owo gidi to gbe ibon nii to tun sise isora. 08160766218