04/04/2026
*ALA ATI ITUMO PELU ỌNA ABAYỌ*
ènìyàn kan ma ùn bẹrẹ pè se àwọn ala ti ènìyàn ba la ni ọsan kìí ùn wá sì imuse ni?
Nje iwọ mọ pé kòsí igba tabi àkókò ti eda ènìyàn kólé lala níwọ̀nba igba ti orun bati pa oju wa de.
Bíi obalala pè òun jẹ pawpaw loju ala
Ìtumọ:- ikan irọrun nla kan nbọ wa ṣẹlẹ sì rẹ laipẹ.
Bíi obalala pè ikan ti oun wa loju aiye bọ sì fún rẹ loju ala
Ìtumọ:- oni lati mura dada kìí etí mase ṣẹlẹ sie.
Bíi obalala pè oni oyun 🤰🏻 loju ala ti osi bímọ sugbọn loju aiye kòsí oyun ninu rẹ
Even oti ṣiwọ ọmọ bíbí gan loju ayé
Ìtumọ:- laipẹ ikan àríwo nla kan nbọ wa ṣẹlẹ sì rẹ.
Bíi obalala pè wón ùn bá rẹ fọ Irun 💆🏻♂️ ori rẹ loju ala
Ìtumọ:- ogo rẹ yóò gba ayi pada rere laipẹ.
Bíi obalala pè òun mu ọti agogoro🍻 loju ala
Ìtumọ:- tẹra mọ adua kí omase tosí laipẹ.
Bíi obalala pè wón fún ee ni àtùpà 🪔💡 loju ala
Ìtumọ:- ọna yóò ma la fún ee ni gbogbo ọnà.
Bíi obalala pè òun pọn omí 🚰 🪣 loju ala ni gbogbo igba
Ìtumọ:- wa ma ni àkójọ oore ni gbogbo ọnà.
Bíi obalala pè òun wọ ara-re ninu jìgì 🪞 🪞 loju ala
Ìtumọ:- wa ni ibasepọ pẹlú àwọn ènìyàn rere.
Bíi obalala pè wón fún ee ni 🧷 loju ala
Ìtumọ:- wa se àṣeyọrí ni gbogbo ọnà
Aye koni pa iná 🔥 ogo ẹmi ati iwọ.