ASIRI EWE & EGBO

ASIRI EWE & EGBO All power belong to Almighty God, don't sleep so that you can move forward and believe me God help those who help them self!!!
(1)

22/05/2020

Mo ki gbogbo ile patapata Lai da enikan si, wipe a ku ojo jimoh ti Toni ,opo re ni ao SE NI oke erupe mo be gbogbo ile ki e maa binu Simi wipe o to ojo meta, RAMADAN ni o fa mo si dupe lowo gbogbo eyin ti e n fi adura ranse si mi ATI eyin ti e pemi , olohun o ni jeki a fi iku mo iyin Ara wa, mo tun ki gbogbo MUSLIM wipe a ku opin RAMADAN olohun o ni SE ni opin ni aiye gbogbo wa, amin

12/05/2020

* MA SE WAYE ASAN *
Gbogbo nkan ti olohun da sinu aye daradara ni sugbon Afowofa omo eniyan loman fa wahala ati idaamu sinu aye re , kilode ti wahala Ati idaamu po pupo ninu aye lode Oni ,? Wahala owo ati Idojuko olokan ojokan awon isoro lopoju nisinyi , Sugbon Olori wahala ti a n koju nisinyi meta , meta yi na losi lagbara ju nitoripe Ona meteeta yi ni eniyan tobafe se daada maa gba koja ,
* Ibujoko
* Oogun Aye
* Jija Osi(Wiwa owo)
Mofe sowipe 67% Ni Eniyan tojewipe Won kosini Ile oko tabi tiwon koni iyawo Nile , besini Didalemosu tipoju lode Oni , Gbogbo omobirin ni won koni Ori okunrin mo besini awon okunrin na koju wahala iyawo nini, Kilofa iru wahala bayi lode Oni ? Eyin ojogbon ema bami kalo ninu oro mi nitoripe Awon ona bi meji loman fa iru wahala bee :-
√ Aise iwadi siwaju kia to ni Oko tabi ni iyawo
√ Aini itelorun ati Iteriba fun oko
Iwadi se Pataki ninu aye omo eda nitorina Ejeki a maase iwadi ohun Gbogbo siwaju igbese ,Ni aye Atijo awon Baba wa maa gbiyanju Latise iwadi siwaju nini oko tabi Aya ,
* Eleekeji Ni wipe Didojuko Isoro Awon Ota , Ranti wipe Gbogbo eniti o ba fe je Eniyan ninu aye gbodo ni Isoro besini inu ina ni wura ati fadaka la koja, masejeki Isoro bori re , gbiyanju lati bori Isoro , sunmo awon onimimo kí wọn fi ona mon. latimo nkan ti eleda re n fe ati nkan ti kofe,
*Eleketa ni jija Ogun osi , eniyan gbodo jagun osi kuro ninu aye re nitoripe Olohun koda enikookan wasile aye lasan lainidi kan pato besini igbiyanju die ni Elomiran n fe ninu aye re sugbon ailejade ati jijoko tetere lose okunfa osi ati Wahala sinu aye re. Ma se waye Asan, Ma se joko sojukan na , Ise onise ni Elomiran n se , Aya alaya ni Elomiran fe sile , gbiyanju latimo iru irawo re pelu ohun toromo irawo re

08/05/2020

ISE IYONU TI A FI MAPADE ALANU

ao wa ewe ewuro oojo, epo obo die ,imi orun

Ao lo meteta lototo ao wa ko ni ose dudu tabi Ghana , ao mu owo eyo eyo kan ao fi gun ni ori, ao ma we ni larolaro

Gbolohun
Ajiromotutu 3x
Akiromokuku 3x
Osaa ile asarijiki 3x

Wa sare tete lati isalu orun wa si isalu aiye ki o la ona ire owo nlanla kan emi lagbaja omo lagbaja Loni ,nitori wipe ojumo o ni mo ki ojumo maala ojumo ti o mo mi Loni ki oro mi dun nitori adun ni gbeyin ewuro, aje ,oso ,ati gbogbo aburu aiye kogbodo de odo mi, nitori epo obo ni o npin awon eleye, eye keye ti o baje obo orun lala , ati omode ati agbalagba ti o ba fe di mi lowo ki won ba won gbe ni ajule orun, jatijati rede rede ni koba gbogbo eyin ota mi, ki emi lagbaja omo lagbaja ri taje se nitori aje ki won ni ile olokun, aje o gbodo won mi gbogbo ibi ti owo ire gbogbo ba wa ni o ni ko maa wa je temi lagbaja omo lagbaja

ASIRI TI OGUN O KI FI JE FUN OPOLOPO ENIYANpupo ninu awon eniyan ni won maa so wipe ogun dudu o ki sise fun awon, opolop...
03/05/2020

ASIRI TI OGUN O KI FI JE FUN OPOLOPO ENIYAN

pupo ninu awon eniyan ni won maa so wipe ogun dudu o ki sise fun awon, opolopo lo AJEGUN t**i sibe ko je fun won ,awon asiri ti ogun dudu o ki fi nje die ninu re ni mo fe so

1, awon irawo kan nbe ti ogun dudu o ki Saba sise fun, ki won fi 1million jo ogun won o le ri 1,ooo

2, awon irawo kan nbe ti ose wiwe o gbodo po fun ti won ba se be ogun o NI je mo

3, Awon ise kan nbe ti o NI majemu sungbon to ri wipe ao San majemu re koni sise

4, Pupo ninu awon ti won n ta leku leja ni won o ki see otito pelu awon oni ibara won

5, gbogbo àwọn ti won ba fun yin ni ise koni won fun yin pe

6, opo eniyan ni won ti ba nkan ti asiri o fi maa je mo lara

7, opolopo eniyan ti ogun o ki nje fun ni won ni egbe ti egbe si nda laamu

8,Sise nkan eewo (forbidden) ko ki nje ki ise je

9, gbogbo okunrin ti iyawo re baje esu leyin ibeji fun wahalai ogun o NI je fu

10, gbogbo obinrin ti o won ba je eyin ti o ti fi aye won rin irin Ajo ogun o NI je fun won

E darapo mo WhatsApp group wa

https://chat.whatsapp.com/J6vVpJbTMLSGciS6BKN6tY

WhatsApp Group Invite

03/05/2020

ASIRI BIBO TI O YAWERE GANN

ewe bomubomu ti o fe daada mejo
Eyin ororo ti o mo daada merin
Ao ko eyin ororo yii sinu ewe bomubomu ao Po bi won se npon moimoi pelu ewe mejejo, ao we pelu owu imule
Ao gbe sinu ape titun oti schenap ni ao fi se ti o ba tutu ao se adura si ao je
Pelu ogo olohun ao ri owo ti ko ba ni owo aye ninu

22/04/2020

OGUN OSE ATUDE
ERU Alamo die
Egbo tude
ATA wewe
Ose Dudu
Aogun papo dada mon ose ewe ojo meta
Lilore: Ao pin ose yen si ona meta aofiwe ni ale fun ojo meta gbako
Ojo Akoko:Ao fi Epo pupa para lati ori dele
Ojo keji :Ao fi ori para lati ori dele
Ojo keta: Ao fi oyin para lati ori dele
Nb: Fun ojo meta ti aofi we iwe yen ako gbodo jade sita man ooo

17/04/2020

♈♉♒♊♐♋♎♓♏♍♑♌ *ALAAYE IRAWO EDA*

*AWON OMO EGBE ORUN ATI TAYE*

(1)
Awon àmì tí ẹni kọ̀ọ̀kan yio fi máa dá ara rẹ mọ nìyí àti àkíyèsí tó dájú, Rio baje ọmọ ẹgbẹ́ AMU TORUN WA, kiise gbogbo ọ̀rọ̀ ni wàá máa fi ṣe awada nítorí gbogbo ọ̀rọ̀ enure tase tase ni gbogbo nkan tio bawi yio ri bẹẹ

(2) Bi ọkọ ilé wọn ba toju wọn daradara tí inú wọn sì dùn sí ọkọ náà Bio ba jade lòsi ibi ìṣe oojo rẹ yio rise dáadáa lọ́jọ́ náà yio ri (DOUBLE) owó tọ̀nà fún ìyá wo rẹ

(3) Omo elegbe orun man ni ẹ̀bùn àlá daada gbogbo nkan ti yio ba sẹlẹ si wọn tàbí ara ile wọn ní yio hàn sí wọn ketepe loju àlá wọn

(4) Bi eniyan ba jamba ọmọ elegbe amu torun wá ti omijé fi bo sílè loju rẹ ìyá ìlọ́po ni yio je eni tó jamba wọn yẹn bí wọn ba paro mọ wọn tí inure fi baje ibanuje ayé ráyè ni yio sele sì ẹni tó paro mọ wọn ayaa fi tio ba tọrọ aforijin ni ìyá náà koni pọ

(5) Bi Ọmọ elegbe amu torun wá bá ń bae joko síbi ojare SHOP, île ise bebelo, Oja re yio maata wàrà wàrà irú àpẹẹrẹ bayi ni awon ìyá wá àyè àti jọ Man lo tí wọn ban kiri oja wọn yio ni kí enikan ó báwọn gba owó yẹn lowo ẹniti wọn tá oja fún kí wọn ó tó gbà á padà lọwọ rẹ tí wọn Bati mo wípé ọwọ ẹni toba àwọn gbowó owó aje ni ọjọ́ ojúmọ́ òun ni wọn yio maa wa kio bá àwọn gbowó,

♈♉♒♊♐♋♎♓♏♍♑♌

16/04/2020

IWULO EKURU FUNFUN
APA KEJI
(1)

Bi eniyan baje òní sowo ńlá tí ọja rẹ man dín kù laimo ẹni tó ń yọ oja re bio ba mu ekuru funfun kio roo papo mo iyọ, tàbí oyin kio fọn ekuru yi si gbogbo ọjà yí oja rẹ koni dín mo yóò sì tà daada

(2)

Bi eniyan ba saaba man je ekuru daada àṣírí ìkòkò nípa ọ̀rọ̀ arare yio ma hàn sie wàá má rí sì payá nípa ayé rẹ lójú orun daada

(3)
Kosi iseda irawo tí kole je ekuru tàbí láti fi ṣe saara fún ènìyàn gbogbo iseda irawo ni ekuru wúlò fún

(4)

Bi eniyan ba saaba man je gbese tàbí tí owó kii dúró sowo ènìyàn ṣe ekuru yi ko pò kio haa fún gbogbo ènìyàn kio si gbe ìyókù losi àárín oja kio lọ fi ṣe saara fún àwọn ayẹwo gboore waari ìyàtò daada

(5)

Ni ayajo ọjọ́ Birthday rẹ tio ba kọ́kọ́ ṣe ekuru yi fún gbogbo ènìyàn tio sì pẹpẹ àdúrà sii bóyá Alfa rẹ tàbí pastor rẹ, ki wọn ṣe adua fune waari ìyàtò rere nínú ayé rẹ

(6)

Bi eniyan ba sese ra ilé tio fé kole sori ẹ tio ba kọ́kọ́ ṣe ekuru yi pelu oyin àti iyọ tio fi roo daada kio wá fọn sì orí ilé yẹn daada Bio ba se bẹẹ bí emeta kio tó bere ilé náà arisiki àti ìbùkún yio dúró sí orí ilé yẹn gbogbo enit toba gbé inú ilé naa koni mo ìnira àwọn èmi okun kun kàn kan kosi lè dúró sórí ilé náà láéláé

(7)

Bi eniyan baje elegbe ọmọ tio ba nda ekuru sínú odò lanla sungbon rii wipe odò tí ẹja bawa ninu rẹ loda ekuru náà sio gbogbo nkan yio dero fune ayaa fi tí ogun ìdílé bapo fún irú ẹni bẹẹ nítorí bí ogún ìdílé bapo fún ènìyàn kiije ki Ọmọ ologo ó tètè rise.
Ogode èmi pín konije ìpín èmi àti ẹyin.

16/04/2020

BAMI GBIYANJU ASIRI YI WO
FUN BI ASIKOYI SERII

ASEJE BIBO ASIRI TO CONFIRME DAADA

Eko elewe kan, ao bo ewe ara eko naa
sinu ike fun fun kan, ao waamu die ninu ewe eko yen, aopaapo mo Ewe Ola die, Ewe sawerepepe oojo, Ewe awoyoyo oojo, iyere die, ao lo won papo. Aofi se ponmo
sisun ti a ge si ona meje lepo niyo
Ti o ba jinna tan, ao so sori Osuka kan a*o fun fun kan
JIJE RE:
Ao fi Eko ti abo ewe lara re sinu aseje naa, ao waa se adura si daada , ao wa koje,
hmmmm Danwo kodupe lowo Olohun oba Toni Asiri

12/04/2020

Gbogbo omo leyin Cristian ni Moki ku ODUN ooo

12/04/2020

MOKI WA KU OJO MEJI META OKE YII NI KO JE KI A RI TOHUN

AWON ÈNÌYÀN KII FURA LÓRÍ ÌRÌN ÀJÒ AYE WON GBOGBO ÌṢÒRO NI WON MA N PENI OWÓ AYE BEE SINI KORI BEE

(1)

Èlò miran yio maa so wipe gbogbo nkan ti oun ba fe se laye kii bosi boun se fe tabi ko tie ma seese rara die lara nkan tó n fa nìyí oni lati mo iru iseda ti Ọlọ́run dae boya gbogbo nkan tio bati fe dawole tabi ti o fe se oo gbọdọ sọọ sita - (SAY IT OUT)
bio bati soo sita gbogbo kan tio fe se tabi( PROMISE) Ti se ni adeun fune koni bosi mo

(2)

Bákan náà iseda ẹlòmíràn kii ba eniyan da ise papò bio ba ba eniyan da ise po eo ja tuka gbogbo owó yio tuka moe lọwọ

(3)

iseda ẹlòmíràn kii ya ènìyàn lowo (money) tabi a*o tabi Oun koun nítorí ẹniti o ba ya lowo won koni daa pada fun e mo ija ni yio pada gbeyin nkan tio ya ore tabi egbon re naa E. T. C

(4)

Iseda ẹlòmíràn kii soore aseju nítorí ibi ni won yio fi san ire fune sungbon iru eniyan bee ko gbọ́dọ̀ jawo ninu oore nítorí yio pada jere re lọ́jọ́ iwájú

(5)
Iseda ẹlòmíràn kii ko ore nítorí won yio maa binu re láìnídìí Wọ́n yio maa wa isubu re ni gbogbo ìgbà bakan naa won yio maa ba e je kaa kiri

(6)
Iseda ẹlòmíràn kò gbọ́dọ̀ fi adé ogo re sise labe ẹlòmíràn iru eni bee koni tete dide bakan naa owó koni duro lọ́wọ́ re

(7)
Iseda ẹlòmíràn kii wo a*o aloku boya a*o ore re tabi a*o egbon re ayaa fi toba je wipe eni to fun un la*o koti fi orun kan a*o naa tio je tún tún ole loo to banlo a*o aloku iru eni bee orisirisi isoro ni yio maa koju re

(8)

Iseda ẹlomiran kii jeun kaa kiri nítorí ki won oma lo fun un ni ounje ti koba iseda re mu

(9)Ninu irin ajo aye ẹlòmíràn olójú ounje tó bá iseda re mu toba ti je nkan ti iseda re kofe èyí ma n fa ki awon ota ora ye wole sinu iseda ogo aye re ti gbogbo nkan yio si daru mo eni naa lọwọ

(10)

Ninu irin ajo aye iseda ẹlòmíràn kii pari wo iru awon eniyan bayi gbọ́dọ̀ gbo ikilo daada sungbon o wọpọ nínú wọn ti kii ka iru ikilọ bayi kun osi man fa wàhálà púpò si ènìyàn lorun ole fa iku òjìji, ole gba arisiki danu lọwọ eni, ole da igbeyawo ru ole gba ise danu lọwọ ọkọ ati iyawo ati bee bee lọ
MO FI ELEYI KI WA KU ODUN AJINDE O NI OPO RE NI AO SE NI OKE ERUPE

25/03/2020

*IBUJOKO*

Ibujoko je nkan pataki ninu aye eda laye, ti koba si ibujoko ninu aye eda iru eda be kole se aseyori laye, ibujoko ni ibi isinmi eda, bi obirin koba ti de ibi ibujoko re yio ma ko kiri ni gbogbo okunrin ni yio dabi eniyan buruku loju re, be bi okunrin koba ti ri ibujoko re gbogbo obirin to n ba fe ni won yio ma gbeju sile, gbogbo obirin ni yio dabi eniyan buruku loju oun na, Bi eda ba se ise onise iru eda be koni de ibujoko ayo o di ojo ti o ba se ise ti Olorun ran koto to le joko lori ibujoko ayo, ki eniyan tole de ibujoko ayo orisi nkan ni yio la koja kotode ibe, opo awon to fi se igbekele ninu aye nigba toba ya won o pada ja kule ni ikorita aseyori mafi se ibinu iru won ni won pe ni asunnibare, a lo won fun re lati tete de ibujoko re ni mari won bi eniyen buruku laye, ninu ilakoja re Olorun yio ma si re kuro ni ipo kan bosi ipo kan nigba miran o le kuro ninu ipo dada bosi ipo idakeji ma tori eyi soro buburu si Olorun tori Olorun mo ibi ton mu re lo, nigba mi ipo ti elomi wa loju ara re ipo toda ni sungbo niwaju Olorun koki se ibuko ayo niyen fun igba die ni ibi towa yen, nigba toba tun ba ara re ninu ipo ibanuje dakun ma banuje gba gege bi ayo, bi o ba ranti itan Anabi Yusuf amu kuro ni ipo kan bosi ipo kan lati ipo eru bosi ipo tubu lati ipo tubu bosi ipo ibujoko ayo ayeraye lati igbayen Anabi Yusuf kori ibanuje mo, Olorun mo idi pataki to yi fi wa ni ipo towa yen iwo sa ma gbadura kosi ma ni ireti bopeboya wa de ibujoko re, mo wi gege bi ẸRÚ Olorun alaye pe ipo ibanuje towa yen Olorun komu re kuro nibe bosi ipo ogo, ibiti aga ibujoko Ayo re wa ki osu yi to pari Olorun ipe komu re debe, enikeni toba wa lori aga ibujoko Ayo re Olorun ipe kofi ina si nidi ki iwo le raye joko pada, ibujoko ayo re ti ika eniyan ti sodi ibujoko ibanuje Olorun ipe ko yi pada si Ibujoko ogo iru ika eniyan be ko segbe danu. Amin

AL BAYAD

20/03/2020

*EKUNRERE SAARA SISE FUN GBOGBO IRAWO*

Odara kii Amase saara fun IRAWO wa kii ona lema lafunwa Opolopo Eda nii omope oun nii IRAWO Sugbon kose saara tii oromo ISEDA IRAWO EE kii olohun masejeki kii Awaye asan nii.
Kosi ojoti Akolese saara fun IRAWO wa besini kosi igba tabi Akoko tii Akole see pelu.

*IRAWO INA*

Bii obasakiyesi pe ikan kole deede gbiyanju kii ofi awon ikan yii see saara

Okababa funfun

Agbado pupa

Atii Aadun

Gbiyanju kii omase saara yii pelu Adura lemeji losu bukata ee yio biya pelu ogo lodo olohun.

*IRAWO AFEFE*

Oba irawo kosii gbogbo ibiti Ayekotigba nitoripe obanii
Bii irawo yii bawa ninu Adanwo Kan kii ofii awon ikan wonyii see saara.

Omi

Ounje

Owo
(iyeti Agbara bagbe nii o)

A*o ( eleyi tii obanifesi ju ninu A*o ee.)
Kii ofun awon Afoju ati Arugbo obinrin nii Awon Ikan wonyi.

Pelu ogo lodo olohun bukata ree yii ooo biya

*IRAWO OMI*

Irawo oko Omi je irawo Alagbara tosikunfun opolopo egbe ninu
Gege bii Apere;

EMERE OMI

EMERE

IRANSE AJE

IRANSE OMI

OMI ANU

OMI AJE

EMERE IYEPE

EMERE OKUTA

ETC......
Bi oba wa ninu isorokan tabii ikeji gbiyanju kii ofii awon ikan yii see saara fun eyann tabi kii odasinu odo

Ekuru

Sweet

Biscuits

Osan

Ireke

Sugar

Bukata eee yiio biya pelu ogo lodo olohun.

*IRAWO ERUPE*

Bii edatii oun lo irawo yii bani isoro kii ogbiyanju latii mafii awon ikan wonyii se saara kii ona letunbo lafun.

Oyi

Epo pupa

Isu

Agbon

AL BAYAD
MO KI GBOGBO WA KU JIMOH TI O NI OPO RE NI AO SE NI OKE ERUPE

IKEEDE! IKEEDE!! IKEEDE!!!Ona meta ni Eda ngba ni adanwo ni aiye1, AMUWA LATI ODO OLOHUN2, AFOWO FAA3, AFISEmeteta ni o ...
19/03/2020

IKEEDE! IKEEDE!! IKEEDE!!!
Ona meta ni Eda ngba ni adanwo ni aiye
1, AMUWA LATI ODO OLOHUN
2, AFOWO FAA
3, AFISE

meteta ni o ni ogun, mo mu awon idi meteta wa ki a le mo wipe gbogbo nkan ko ni a fise, gbogbo adanwo tabi aburu ti o de ba Eda ni OSE, ASEJE TABI IPESE lee jeki eniyan o ri ona abayo , opolopo ti we ose iru dudu ti di funfun , opolopo ni koni igbagbo ninu ogun mo nitori kosi iyekiye ti ko ti naa Lori ogun iro naa ni o jasi
Opolopo ni o ti se ese(leg) gbe latara nkan ti o Lodi si irawo re
Opolopo ni o se ise onise ti o npa ariwo wipe aiye nse ohun
Opolopo lo he wipe lati igba ti won ti ni oko tabi iyawo ni wahala ti de si inu aiye won

An fani wa fun eniti o ba fe mo nipa IRAWO re ni ekun rere ki o bami soro Lori WhatsApp 08075619161

If you want to know about your horoscope full details about your destiny
Contact me on Whatsapp
08075619161

19/03/2020

AGBELEKPOTA TO GBONA... LARIN OJO MEJE AWON OTA WA WON MA KU BI ADIE NI.
Ada tuntun.
Agbon odindi kan to lomi ninu kan.
Epo obo.
Ose dudu.
Ike white.
Sise re.... Ao gbe ada yi sinu ina ko gbona na daaada ko pon daaada,
Ao ti gun epo obo ninu odo ko kuna daaada ao wa po lose ninu odo na.....ti ada yi bati kpon daaada ao wa gun le lori ose yi lori odo.... ao wa fo agbon yen lelori ada yen lati ori ada yen omi re yio ma bowa sinu ose towa ninu odo na...... Ao wa yo ada yen kuro ao wa po ose yen daaada ao ko sinu Ike funfun.... Ao wa we ada yen ni a*o pupa ao lo bomole bi oku. Ao ma we ose yen lale.

19/03/2020

ILEKE ADODUN TI OBINRIN FI NGBOWO LOWO OKUNRIN
Eyikeyi ileke toba wu obinrin,ewe omisinmisin mejeeji tutu,ewe sikinrinmidin tutu,ewe agboyun tutu,ao gunpo,ao ko sinu igba olomori kan,ao wa han: 313×,ao da sinu igba yen,ao ko ileke na si,ao Wa da oyin igan topo le lori,lehin ojo keje ni lilore yio bere

18/03/2020

ASEJE BIBO ASIRI
Edo malu ti ko wo omi agesi 7 a loo mo nigedegede ti aja ni oojo ati epo jebo ati iyere afi se edo malu je afi
epo ati iyo si, a*o funfun lafi se osuka re taa so le lori tabi kalo roro ogede ase adura si awaje.mofi olohun
bura tiko basi owo lara eni to fe se fun yan tabi eniti won ba se fun yio ri owo ope ju ojo keta

EYONU AYE TAARA TODAJU... 100%_tested and confirmedEwe olomisinmisin pupo tutu oojo die, Ao gun papo Mon ose dudu, ao ni...
18/03/2020

EYONU AYE TAARA TODAJU...
100%_tested and confirmed

Ewe olomisinmisin pupo tutu oojo die, Ao gun papo Mon ose dudu, ao ni fi inkan po o, Ao ko sori #10 mefa
Ao we lojo mefa Lera

Walai ti eeyan bafe se interview, abi o fe gba contract abi, omo yahoo lo, abi onitaja, Yi o pada dupe..

Gbolohun re
Olomisinmisin ki NPA ohun Orissa oke Da, ki won male pa ohun mi da
Ose loni kose loni...

Ao fi #10 yen lose saara lojo kefa fun onibara mefa ototo...

16/03/2020

*EYONU AYE TO DARA*
Ewe Orijin, Ewe Afeloru, Eru alamo, Epo Obo, Epo iginla. Ao gun gbogbo re papo daada. Ao pomo ose dudu. Ao ma fi we ni gbogbo igba pelu omi tutu....

*OGUN EYONU ASIRI BIBO*
Ewe orijin ao ja ti yio po ao tole ori ara won, odidi atare kan, eyin adie ibile to mo daadaaa kan, Omo ayo meje, ao jo po ao dasi ona meta idakan inu oyin, idakeji ao po mo ose dudu, idaketa ao da sinu ipara eyi keyi pelu lofinda to ni orun daadaa, ao mafi para odaju saka.

14/03/2020

Igbesi aye omo lati owo obi ni gbogbo omo eniyan ngbe patapata, nitorie pe ti obi ba si iwa hu, afaimo ki omo won naa ma si ile aye gbe*

Awon ohun idenan ririse eda laye, obère
1) lati ibi ibalopo obi,
2) lati inu oyun
de ibi omo tuntun ti oyinbo npe ni placinta

IBI ỌMỌ TUNTUN

Ibi ọmọ tuntun ṣe pàtàkì nínú irin àjò ayé ọmọ sungbon aimokan koje kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn leka kún pelu ẹ
(1)
Kodara kí ènìyàn oma sìn ibi ọmọ sójú ona ti gbogbo ènìyàn ngba kọjá olè wù Ọlọhun mase ọmọ wa leru egbe rẹ láyé kiije ki eniyan le ni agbega láyé
(2)
Kodara láti máa ju ibi ọmọ sórí akitan tàbí inú salanga olewu Oman fà àmín ìkórìíra fún ọmọ bẹẹ

(3)
Kodara láti máa gbé ibi ọmọ fún aja je olewu irú ọmọ bẹẹ yio yà aṣẹ́wó gidi gbogbo ìgbà lémi rẹ yio maa wa lọdọ orisirisi ọkùnrin fún àgbèrè sise

(4)
Kodara láti máa sìn ibi ọmọ sì agbo ọ̀gẹ̀dẹ̀ nítorí àwọn ọmọ emere ki wọn oma bàa fi èmi kemi sii lára
(5)
Kodara láti máa dáná sún ibi ọmọ ayafi ti ọmọ baa baje abiku ọmọ tí wọn fi ṣe aájò kí oma lè padà lọ mọ nìkan loku nítorí tí kò baje bẹẹ ọmọ tiwon basun ibi rẹ wàhálà yio pò fún nínú irin àjò ayé rẹ

(6)
Kodara láti máa ju ibi ọmọ sínú agbára ojo Tàbí nínú Odò

(7)
Kodara láti máa sìn ibi ọmọ sì àwọn ènìyàn nda ìtó sì.

(8)
Aimoye ona ni àwọn ojogbon má ń gba láti fi sìn ibi ọmọ

(9)Eniyan le sìn ibi ọmọ lailo ìkòkò tàbí ìgbà ademu ao gbé ilé sì ibi tó bá tútù daada ao gbe ibi ọmọ yi ju sínú rè ao bù iyọ̀ leè lórí pelu epo Pupa bákan náà àtun lè fi oyin sii tàbí orí ao wá bù omi tútù sii lórí irin ajo ayé ọmọ náà yio rọrùn daada

(10)
Eniyan le lo ìgbà ademu lanla tàbí ìkòkò aseje ńlá aogbe ibi ọmọ yí sínú rẹ lásán ao wá owó ẹyọ iye yowu ao gbé lé níbi toba tútù daada ao gbé sínú rẹ ao wá yepe boo mole Ao tún fi omi wọn lórí daada

(11)
Ale gbé ilé lẹgbẹ baluwe kí ari ibi ọmọ síbè súngbon olewu die nítorí àwọn ènìyàn tún man fi Seka fún ara wọn nítorí ibiti koba sì ìfẹ́ gidi ti ìjà bawa laarin iyale tàbí ìyàwó wọn lé lọ wù ibi ọmọ yí leyin láti fi ṣe ìkà fún ara wọn sungbon ibi tí ìfẹ́ òtítọ́ bawa àlè rii mo baluwe kosa tije ibi tó tútù daada

(12)
Ale rí ibi ọmọ sì inú igbó ao gbé ilé tí yio jin daada àleri ibi ọmọ sì inú abata etí odò tàbí ara ile bákan náà bákan náà àlè gbé ibi ọmọ sínú aṣọ funfun kí arii mọ́lẹ̀ bẹẹ ó dára pupọ

(13)
Eniti ona rẹ bajin bóyá ìlú Oyinbo tàbí tí kosi ibi tole rí ibi ọmọ náà sì Ao ṣe adua sì ibi ọmọ yí daada ao wá bù omi tútù sii ao sin gege bí wọn ba se n sìn ibi ọmọ ni orile Ede náà kosi laburu kan kan nibe.
Ọlọ́run yio se gbogbo àwọn ọmọ wa lolu ọmọ ó amin

AWON EGBO IGI TI ODARA FUN IRAWO RE1.IRAWO AFEFEJe eniti yio maa se Adua daadaa ,ki o si maa tan Turari pupo ni igba ti ...
11/03/2020

AWON EGBO IGI TI ODARA FUN IRAWO RE
1.IRAWO AFEFE
Je eniti yio maa se Adua daadaa ,ki o si maa tan Turari pupo ni igba ti o baa
nse Adua lowo, Maa lo Turari Adua dada ni gbogbo igba,Aseje,Ose,ati Ebu ntete
maa n sise lara iru irawo yii ni di won ti won baa n ti nse adua ki won too lo

2.IRAWO OMI
Ki won je iru Eda ti o nlo unkan ti won fi omi pe se re, gege bi Hantu mumu,
Obe Aseje tabi ki won maa we ose dudu.Ebu Jijo ki sise lara won,bi won baa fi
one million se ebu fun iru won ko leri one naira niibe.

3.IRAWO INA
Irawo ina gbodo sora fun wiwe ose ni gbogbo igba,Ohun ti o da ra fun iru
irawo yii naa ni Ki won maa lo Ebu ti ajo..Ebu ni o nsaba maa sise pupo fun won
ju gbogbo ogun miran lo, Awon Ogun miran naa maa nsise fun won sugbon ko
dabi ki won lo Ebu

4.IRAWO IYEPE
Irawo yii gbodo maa se Sara Daadaa, ki won maa fon awon nkan jije si ile
fun awon eda ti won nse aiye iyepe, Ose Dudu ati Aseje dara pupo fun won

ORO NBO LORI ISE YII FUN ENITI OKO ORUN NDA LAAMU
10/03/2020

ORO NBO LORI ISE YII FUN ENITI OKO ORUN NDA LAAMU

10/03/2020

ONFA OWO TODAJU
Ewe ejinrin tt pupo, ori olongbo toni irun kan, owo eyo gidi 9/16, atare nla kan SISE....Ao ko ewe die tele ape, ao gbe ori musu le, ao wa to owo eyo ye yika ninu ape, ao fi atare ye si, ao wa ko ewe toku bo mole, odi jijo, toba jotan, ao lo kuna, ao mafi otin tabi eko tutu lo lararo.....pelu password yii
OFORE..Ti abafa ejinrin, ejinrin a fa igbo, ki eniti o mo emi L/L lofa eniti ko momi wa, kiwon wa fi owo nlala sise lodomi, nitori ologinni kii dara t**i koma jale, ogundabede olori ole o, bose jiji, bose yiya,bose wiwa, elo dagara owo nla wa funmi lodo omode ati agba, obinrin ati okunrin lati onilo........

08/03/2020

EYONU TI AFIN PADE ALANU TO CONFIRMED DAADA,
ao wa eye adan meta, ao fi enu arawon ko arawon ninu ikoko, ao fi odidi atare kan si arin re, ao ko ewe awopanida sobidire le Lori, ati ewe ola, pelu singa orisi meta, ST,MORIS, BENSON, ROTMAS, eyo meta meta ,ao kole Lori, ao wa Jo papo, ao ro sinu sere kan, ao mafi fokomu lararo kutukutu, ao je kolo bi 2 hour larawa kato jade sita oo, hmmmmmm confirmed ni ooo,

06/03/2020

ASIRI OWO TI ENIKENI KONIMO BI OWO SE WOLE.

Igbin to gbonu meta.
Odidi ijapa meta.
Eyin oronron 5.
Eye igun.
Adie ako ati abo.
Ewe alupaida.
A*o funfun opa meta.
Sise re:-ao gbe gbo gbo awon eron ja si nu a*o funfun yen, ao pa awon adie yen ao gbe wo si ao fi a*o yen di won daaada ao wa gbe sinu agbada, ao gbe sori ina ao fi epo pupa yika aro ti afin jo iseyi...ao lo ko kuna daaada ao ma fi pealk milk lo, tabi ki ama fi foko gbigbona mu laaro

Ti koba ye yin e beere oooo

05/03/2020

ORO ISITI RE OOO EJE KAFURA OOoo
Fun awon iwadi timose ati awon Oro timongbo ninu group ati awon Omo egbe ti won message mi•
Ohun lomumi fe post awon Oro yiii•
Awon kan sofun mi wipe inkan koki sise lara awon•
Mowa ronu nipa awon Oro yiii•
Atiwie pelu imon ti ako•
inkan mewa nimo mon pelu imon ti olorun funmi tikoki Eki Aajo ti eyan base kodaun lara eniyan.
1} eniti obanlo ise tobaje. Ose ni kogbodo ma fi a*o nu Ara toba we tan•
2}eni toba lo Aajo ti Aajo na koba irawo re mu Aajo na koni sise lara iru eni bee•
3}ti awon agbalagba bangbe owo le Aajo na ise na koni sise oh•
4}eniti obanlo Aajo ogbodo mase Sarah nitori Aajo pelu manse ise papo•
5}eniti oba nlo Aajo kogbodo ma gbe Emile Aajo na pupo oh tabi ka*o wipe iru enibee gbe Emile Aajo ogbagbe olorun•
6}agbodo ma se eto nigbogbo ibiti abawa nitori apoju ese kokije ki adura gba ati Aajo ti abase•
7}eniti obanlo Aajo gbodo ma Tele ikilo ati awon inkan ti abani ki ese nipa Aajo naa,ejeki Asa bi ologun tini ki Asa•
8}eniti obanlo Aajo kogbodo maje eewo okunrin tabi obinrin eje ka*ora fun eewo jije,ninu awon inkan eewo nipe sinan sise tabi awon iwa bubu ru miran ninu ile tabi Nita.
9} elomiran wa toje wipe adura nikan ati Sarah loyeki omase ti iru enibee banlo Aajo koni sise lara re•
10}elomiran wa toje wipe Aini igbagbo lonse tobatiso si okan re wipe sekini yi masise bayi,iru nkan bee koni sise oh, igbagbo pelu olorun to ni ewe ati egbo lodara julo oh•
Emabinu wipe wahala mi poju sugbon olorun nikan lomon ero okan mi si gbogbo awa omo egbe oh ooo
Sugbon gbogbo igba lomanwumi ki olorun so egbe yiii di apeere rere ju gbogbo awon egbe toku lo•
Sugbon ejeki ase awon akiyesi ti monso yii
Oma wulo funwa ti aba Tele awon Oro mi yi
Atiwipe awon agba sowipe akiyesi oju ogun lo oh oo

AKIYESI PATAKI RE OOoo

AJOGBE AWON IRAWO KONKAN LOTOTOATI LAPAPO FUN GBOGBO AWON TI WONSE DARA PO MOWA ATI AWON TI WON BERELORI AJO GBEPO AWON ...
05/03/2020

AJOGBE AWON IRAWO KONKAN LOTOTO
ATI LAPAPO FUN GBOGBO AWON TI WON
SE DARA PO MOWA ATI AWON TI WON BERE
LORI AJO GBEPO AWON IRAWO

1)Ajogbe Po Adamo Omi ati Omi
Ire Omo Iyami ninu ninu yara yii mofe ki e mo wipe awon Irawo yi ni Ore
won si ni ota awon Irawo Omi ati Omi leefe ara won tabi ki won mu ra won ni
Ore won sile jo da Ise papo.Pelu opolopo suru

2)Ajogbe Po Adamo Omi ati Yerupe
Bakan nani Omi lefe yerupe,won si le mura won ni Ore won si le joda
Ise po Bi oti le jepe yerupe ni Ise ajose yen ma gbe.

3)Ajogbe Po Adamo Omi ati Ina
Lo tito ni opo ninu awon Oni mimo nipa Irawo ko fi owo si ajo gbe Irawo
Omi ati Ina,nitori Omi yoo pada Pa Ina,Sugbon won le jo da Ise po won sile
fera won ti won ko bajo gbe papo lodara ju nitori Ija.Ko da won le ma ba ara
won Sore, sugbon won yoo pada tuka pelu Ija tabi lori Ireje ti yio ma sele larin
ara won pelu aifi nu han ara enitan.

4)Ajogbe Po Adamo Omi ati Afefe
Awon Oni mimo nipa Ijinle Irawo tako Ajogbe Irawo Omi ati Afefe,nitori
wahala ati idamu ti afefe saa ba ma nko ba Omi,sugbon won le fera won gege bi
toko taya won si le jo sore tabi ki won jo da Ise po bi o tije pe won yo tete mari
asise ara won ko si nii si Igbadun fun Afefe pupo nitori Afefe yoo ma fe si Omi
Omi yo si ma tan ka kiri eyi tumo si wipe Omi ni ajogbe won yo gbe pupo.

5)Ajogbe Po Adamo Yerupe ati Yerupe
Ajogbe awon Irawo yerupe ati yerupe dara pupo oore si ma nbe nibe
ajo gbe won Ti o baje wipe yerupe ati yerupe ba fe ara won tabi won mu ra won
ni Ore tabi won jo da Ise po odara pupo won ki si ri Inira tabi Ija rara Afiti
eniyan kan ba wo won larin ni olefa Ituka. Be si ni Adamo yerupe ati Omi naa.

ALAYE SI NTE SIWAJU LORI ORO IRAWO

04/03/2020

TURARI RIRISE
Eku asin gbigbe iyekiye,oga gbigbe,iyekiye ,ao gun po ao tu lofinda bintu kan si,ao po mo daada ao
IKILO
ma fin lale,ko se fin losan rara o ko ma ba faa igbona.

03/03/2020

ASIRI TI OGUN FI N JE
ti a ba Jin ti a ko ti soro si enikeni ao lo si idi igi botuje ao sin gbere yipo orun owo wa mejeji ao ja ewe re ao fi oje re ra gbere naa

03/03/2020

AJEGUN TO TUN MA NSISE KI OWO LE DURO LOWO WA
ase oga.ewe alupaida mesan.eyo atare mesan.ao lo po ao fi sin gbere yipo orun owo wa
mejeji

EYONU TODAJUao wa opolo nla kan,ao la mole ti yio fi ku,ao fiadan si legbe otun ati osi, ao ko aidan le lori,ao fi odidi...
01/03/2020

EYONU TODAJU
ao wa opolo nla kan,ao la mole ti yio fi ku,ao fi
adan si legbe otun ati osi, ao ko aidan le lori,ao fi odidi atare kan si,ao jopo,ao lo kuna,ao ma
fi foko mu larolaro

01/03/2020

IKEDE ! IKEDE!! IKEDE!!!
Moki gbogbo omo edge patapata ,a ku ojo isimi Toni opo re ni ao se ni ori erupe,
Mo layo lati so fun to gbo omo egbe patapata wipe anfani wa fun eniti o ba few darapo mo WhatsApp group wa ki won fi number sile

Ao ma ni anfani lati gbo ohun mi daada Lori gbogbo awon asiri ti mo ba n fisile ti alaye yoo maa waye Lori re daada
Ti a n fani yoo wa fun eyin naa lati beere ibeere Lori ohun kohun

Ti ao si maa soro Lori awon nkan mi ti a ko ni anfani lati so ni Facebook

Drop your contact to join our WhatsApp

29/02/2020

Asiri bibo todaju biku
Ewe bomubomu 60 , eyin pepeye3 atare kan ao ko ewe yen30 sinu ape ijogun ,ao ko 30 tokun le lori jijo po niooo ,ao
pin si ona meta ao fi peak milk lo ni ojo Monday meta okeretan ao ma ri #15,000 tabi jube lo ni ose ose
ti ao fi lo tan
Iseyi daju gan tested and confirmed

29/02/2020

OGUN TAFI MU ENI NTO JIN KANWA
e lo wa esuru tutu ati adin,ao wa ge esuru
yen lori,ao da lu die ao da adin yen si inu iho
esuru ti a pa ni pansa gbolohun pe.....surusuru ni
oro esuru,eniti o ba jinkan bayi ki ara mani
t**i yio fi dapada,ao wa di ni owu dd/ff ao lo
ri mo orita meta.Lagbara olorun inira ni eni
yen ma fi da nkan togbe pada

Address

Alakia , Old Ife Road Ibadan
Ibadan

Telephone

+2348144066473

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ASIRI EWE & EGBO posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to ASIRI EWE & EGBO:

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram

Category