Iwosan Lati Inu Al Qur'an Kareem Lati Owo Alfa AbdulAzeez Onikurani

  • Home
  • Nigeria
  • Ilorin
  • Iwosan Lati Inu Al Qur'an Kareem Lati Owo Alfa AbdulAzeez Onikurani

Iwosan Lati Inu Al Qur'an Kareem Lati Owo Alfa AbdulAzeez Onikurani Onikurani

01/12/2025

ASHIRI ATUDE, PROMISE AND FAIL, ALAKALA, OUNJE OJU ORUN, IBALOPO OJU ORUN, IJAKULE, ISEGUN LORI OTA, ASHIRI YII MO FI SE RE OOOOOO.

Modupe pupo lowo olohun ALLAH ati awon ti won mo ore ti olohun ALLAH se fun won ninu ile alubarika yii pelu awon ashiri ti a n mo fi kalee, modupe pupo lowo awon ti won send owo simi beni awon opo eyan gba number mi naa lori ashiri egun idile ti mo fi kalee, won se won sii ri gbigba adua, Iwo naa se eleyii ko wa dupe lowo olohun ALLAH naa

ENI KI WON BA YIN HAN AYAH AL QUR'AN YII
, فَحَبِطَتْ أَعْمَالُهُمْ فَلَا نُقِيمُ لَهُمْ يَوْمَ الْقِيَامَةِ وَزْنًا 313
leyin ti e han tan e wa fo pelu omi inu agbon leyin ti e ba fi omi agbon fo tan e gbe HANTU yen sibi kan leyin naa e wo ja ewe ewuro oojo to po die e wa gbo ewe ewuro yii ti omi yio jaade ni be leyin naa e wa daa omi ewuro ti e gbo yen mo HANTU yen e wa fi gbogbo e fo gbogbo orii yin,ti e ba ti fi fo ori yin e mo se adua t**i e fi fo ori yin tan, iwo naa mo ya alaimo oree ooooo,, haaaaaaaa lesekese ni e ti mo ri apere pe adua yin gba

SHARE SHARE SHARE

olohun ALLAH yio gba gbogbo adua wa ooooo
WhatsApp number 08073699063
calling number 07085815530

ASHIRI ASHINA AGBEGA TABI SEGUN LORI OTA (ASHIRI SURATUL YUSUF)(1)Alhamdulillahi Robilihalamina 33(2) Astagfirullahi 33(...
27/11/2025

ASHIRI ASHINA AGBEGA TABI SEGUN LORI OTA
(ASHIRI SURATUL YUSUF)
(1)Alhamdulillahi Robilihalamina 33
(2) Astagfirullahi 33
(3) Lailaha ila llahu 33
(4) ALLAHU mo soli ala seyidina Mohamodu waselim 52

ANIYAN LORI ADUA

(1) سورة يوسف ١
(2) وَلَمَّا دَخَلُوا مِنْ حَيْثُ أَمَرَهُمْ أَبُوهُمْ مَّاكَانَ يُغْنِى عَنْهُمْ مِّنَ اللَّهِ مِّنْ شَيْءٍ إِلَّا حَاجَةً فِي نَفْسِ يَعْقُوبَ قَضَٓهَا ٣١٣
(3) دليل الخيرات في رقم 175 من، اللهم ياذا المَنِّ الذى لا يكاف امتنانه ،إلى رقم 187،،3 times

Note::7DAYS NI E FI SE ADUA YII OOOOO
:::: SARAH ADUA YII::E MO FON OKA BABAA, AGBADO,RICE,EEWA,IYO NI OJOJUMO T**I OJO MEJE YIO FI PE,NI OJO KEJE NI E WA PA AKUKO ADIYE KAN ANY COLOUR, E O GE SI ONA MESAN E FI SE SARA FUN ANYBODY

OLOHUN ALLAH YIO GBA GBOGBO ADUA WA 🤲🤲🤲🤲

WhatsApp 08073699063
Calling 07085815530

26/11/2025

ASHIRI SURATUL YASEEN YII WON TI N FUN MI NI TESTIMONY IROYIN AYO LORI OOOOOO I WO NAA DANWO

For any kind of HANTU PRINT WhatsApp number 08073699063
ADUA SURATUL YASEEN TI A N FI BIYA EYIKEYII BUKATA,,,CHAII CONFIRMED GIDI OOOOOO

Awon eyan dupe pupo lowo olohun ALLAH lori ise Lateef 16,641 ti mo fi kalee, won se won sii ri gbigba adura (Alhamdulillahi Robilihalamina Barakah LLAHU fihi)

E ni ki won bayin han suratul Yaseen meje (7)lona MARUN 5 different places

E wa fo HANTU yii sii inu bottle water kekere lona MARUN OOTOTO,e ni jeki omi hantu yen po pipo oooooo deede omi ti e le mu tan lekan naa ni e fi fo HANTU yen oooooo
Leyin naa e wa mu HANTU ti e han yen ni e marun loojo kan naa
E mu ikan ni aaro kutukutu leyin irun ASUBA 6:00 Am or 7:00 Am . elekeje e mu ni 1:00 PM tabi 2:00 PM eleketa e mu ni ago merin 4:00 PM tabi 4:20 pm,elekerin e mu ni ago 7:00 PM tabi 7:10 PM elekarun e mu ni ago 8:00 PM tabi 8:15 PM
Ti e bati fe mu e se adua sii ki e to mu
Haaaaaa confirmed ni oooooo ADUA WA OLOHUN ALLAH YIO GBA GBOGBO E 🤲🤲🤲🤲🤲
:: WHATSAPP NUMBER 08073699063
CALL NUMBER:07085815530

SHARE ADUA YII TORI E LO MI NAng number 07085815530

O fe je ki won feran re nidi business,nibi ise,iyawo tabi oko, contractors,interviews LO DAN MUIBAH YII WO CONFIRMED NI ...
24/11/2025

O fe je ki won feran re nidi business,nibi ise,iyawo tabi oko, contractors,interviews LO DAN MUIBAH YII WO CONFIRMED NI OOOOOO
محبة الكبير(Alfa AbdulAzeez Alfa Onikurani )

Surah Yusuf, Verse 24:
وَلَقَدْ هَمَّتْ بِهِ وَهَمَّ بِهَا 71

Surah Yusuf, Verse 31:
فَلَمَّا رَأَيْنَهُ أَكْبَرْنَهُ وَقَطَّعْنَ أَيْدِيَهُنَّ وَقُلْنَ حَاشَ لِلَّهِ مَا هَٰذَا بَشَرًا إِنْ هَٰذَا إِلَّا مَلَكٌ كَرِيمٌ 71
Surah Ar-Rahman, Verse 58:
كَأَنَّهُنَّ الْيَاقُوتُ وَالْمَرْجَانُ 71

Surah Taha, Verse 39:
وَأَلْقَيْتُ عَلَيْكَ مَحَبَّةً مِّنِّي 71

Ao han ni hantu lona meji ototo.
1.Ao fo alakoko pelu omi ti a le mu tan fun ojo meje,ao mo mu ni aaro kutukutu pelu oyin gidi fun ojo meje(7days)
2.Ao fo pelu omi die ti a le damoo any cream ao mo fi paara

ALFA ABDULAZEEZ ALFA ONIKURANI
WHATSAPP NUMBER 08073699063
CALLING NUMBER 07085815530

CONFIRMED ISE LATEEF NI OOOOOO Alhamdulillahi lori ashiri lateef 16,641 ti mo fi sile won se adua naa won sii ri gbigba ...
22/11/2025

CONFIRMED ISE LATEEF NI OOOOOO
Alhamdulillahi lori ashiri lateef 16,641 ti mo fi sile won se adua naa won sii ri gbigba adua
E TUN GBA ASHIRI LATEEF OLOJO MESAN YII pelu HANTU NAA BAKAN NAA(9DAYS)HAAAAAA IWO SE WO KO FUN NI ABO EHHHHH

ORU BI AGO 2AM TABI 3AM TABI AARO LEYIN IRUN ASUBA BI AGO MEFA 6AM NI ODAAJU TI E BA FE SE ADUA YII

1.ALHAMDULILLAHI 100
2. ASTAGFIRULLAHI 100
3. LAILAH ILALLAHU 100
4.ALLAHUMO SOLI ALA MOHAMMOD WASELIM 92

LEYIN NAA E DANIYAN LORI NKAN TI E FE LODO OLOHUN ALLAH.

(1) YAH LATEEF 9,000

(2) قُلْ مَن يُنَجِّيكُم مِّن ظُلُمَاتِ الْبَرِّ وَالْبَحْرِ تَدْعُونَهُ تَضَرُّعًا وَخُفْيَةً لَّئِنْ أَنجَانَا مِنْ هَٰذِهِ لَنَكُونَنَّ مِنَ الشَّاكِرِينَ
قُلِ اللَّهُ يُنَجِّيكُم مِّنْهَا وَمِن كُلِّ كَرْبٍ ٢٧٠ مرة 270 TIMES
Fun anfani awa ti a mo larubawa ka number 2 ni yii oo eyin copy and paste e so ara yin ooo,ise emi alfaAbdulAzeezAlfaOnikurani (2)
Pronunciation:
"Kool man yunajjikum min dhulumaat-il-barri wal-bahri tada'oonehu tadarrru'an wa khufyah, la'in anjaana min ha'dhee lanakoonanna min-ash-shakirin. Qulillah yunajjikum minha wa min kulli karbin..." 270

SARA FUN ADUA YII LEYIN OJO KESAN(ON THE 9TH DAYS) ::: PALI SUGAR ONIKORO KAN, #500 tabi #1,000 FUN ONIBARA KAN SOSO, OKUNRIN TABI OBINRIN KAN SOSO
OLOHUN ALLAH YIO GBA GBOGBO ADUA WA OOOOOO

E le han hantu re na pelu adua yii

ALFA ABDULAZEEZ ALFA ONIKURANI AL TANKEWWY
WHATSAPP NUMBER 08073699063
CALLING NUMBER 07085815530

ADUA SURATUL YASEEN TI A N FI BIYA EYIKEYII BUKATA,,,CHAII CONFIRMED GIDI OOOOOOAwon eyan dupe pupo lowo olohun ALLAH lo...
20/11/2025

ADUA SURATUL YASEEN TI A N FI BIYA EYIKEYII BUKATA,,,CHAII CONFIRMED GIDI OOOOOO

Awon eyan dupe pupo lowo olohun ALLAH lori ise Lateef 16,641 ti mo fi kalee, won se won sii ri gbigba adura (Alhamdulillahi Robilihalamina Barakah LLAHU fihi)

E ni ki won bayin han suratul Yaseen meje (7)lona MARUN 5 different places

E wa fo HANTU yii sii inu bottle water kekere lona MARUN OOTOTO,e ni jeki omi hantu yen po pipo oooooo deede omi ti e le mu tan lekan naa ni e fi fo HANTU yen oooooo
Leyin naa e wa mu HANTU ti e han yen ni e marun loojo kan naa
E mu ikan ni aaro kutukutu leyin irun ASUBA 6:00 Am or 7:00 Am . elekeje e mu ni 1:00 PM tabi 2:00 PM eleketa e mu ni ago merin 4:00 PM tabi 4:20 pm,elekerin e mu ni ago 7:00 PM tabi 7:10 PM elekarun e mu ni ago 8:00 PM tabi 8:15 PM
Ti e bati fe mu e se adua sii ki e to mu
Haaaaaa confirmed ni oooooo ADUA WA OLOHUN ALLAH YIO GBA GBOGBO E 🤲🤲🤲🤲🤲
:: WHATSAPP NUMBER 08073699063
CALL NUMBER:07085815530

SHARE ADUA YII TORI E LO MI NA

19/11/2025

Ashiri Hasbunalahi fun ashiri bibo pelu ASHINA OWO NLANLA, very soon INSHA ALLAHU

oya eyin eyan mi e je ki a share!!!!

15/11/2025
13/11/2025

YAH LATEEF asiri yiI lagbara pupo awon agbalagba ma n fi bi ya bukata kiakia ni

A o se aluwala a o wo a*o funfun a o fi any turari oloru Sara a o wa Yan nafilah meji a o salamo a ose (mukodimat,ALHAMDULILLAHI 33,ASTAGFIRULLAHI 33, LAILAH ILALLAHU 33,ALLAHUMO SOLI ALA MOHAMMOD WASELIM 92)a o wa daniyan a o gbe alquran a o si suratul kahaf سورۃ الكهف a o ma ka ti aba ti de ibi wali yatalatofu وليتلطف a o duro sibe a o wa se yah lateef 16,641 (16,641ياللطيف) ti aba tiparire a o wa daniyan Lori nkan ti a fe. a o wa pari suratul kahaf dele a otun da aniyan wa pada....ti ABA tise tan opari....ejeki asa iseyin fun ojo meta tabi ojo meje pere leyin ojo keta tabi ojo keje,, a o se Sara re....agbon eyokan,orange meta,ogede jije idi kan #1000 ao fi gbogbo awon nkan won yii se sara fun( ANYBODY NINU ONIBARA kan SOSO OKUNRIN TABI OBINRIN) ORU NI E SE ADUA YIII OOOOOO BI AGO (MEJI 2:00AM TABI META 3:00AM ORU)inshallah ise todaju ni Walahi talahi asiri Inu Ile ni...enikeni tobasa iseyi tikobari gbigba adura re haaa ki eni naa komu ra dada....ide pofun ni....olohun ajeki o je funwa Inshallah....

WhatsApp number
08073699063
calling number
07085815530

ISE ASHIRI ASHINA OWO, CONNECTION TO CONFIRM GANAsallam Alaykunm Waramotulahi Wabarakatu gbogbo ile adua wa yio gba oooo...
13/11/2025

ISE ASHIRI ASHINA OWO, CONNECTION TO CONFIRM GAN

Asallam Alaykunm Waramotulahi Wabarakatu gbogbo ile adua wa yio gba oooooo

Eleyii ni ise Suratul Yasin, Suratul Waqia, Suratul Muliku to sise

Owo NLANLA
ANU
ISHINA TO CONFIRM

Ao han hantu
SURATUL YASEEN 83
SURATUL WAQIA 96
SURATUL MULIKU 30

Ao fo hantu yii pelu omi to mo daada sinu ike 5 liter keg, Ao mo mu hantu yii ni aaro kutukutu bi ago (6:00am abi 7:00am) pelu oyin original fun (9 days)

HANTU elekeji nani

(1)Laola walakuwata hila bila lihaliyu lihazeezm 2035
(2) lihilafi kureshin 77
(3) hayyatul kurisiyu 170
(4) Birobili falaq 111
(5) Brobi Nass 111

E fo hantu eleyii naa sinu ike 5 liter bakanna ( watch it inside another 5 liter keg) ao wa lo wa sidru powder a wa da sinu hantu yii,ao mo da diedie sinu omi iwe wa,ao mo fi we ni ale bi ago mesan abi mewa si mokanla ale ( 9:00 pm or 10:00 pm or 11:00 pm) fun ojo mesan (9 days

Olohun yio gba adua gbogbo wa oooooo 🤲🤲

WhatsAppnumber;;08073699063
Call number:: 07085815530

For any HANTU call or whatsapp 08073699063

Address

Tanke Bubu
Ilorin

Telephone

+2348073699063

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Iwosan Lati Inu Al Qur'an Kareem Lati Owo Alfa AbdulAzeez Onikurani posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Iwosan Lati Inu Al Qur'an Kareem Lati Owo Alfa AbdulAzeez Onikurani:

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram