22/04/2026
Ọ𝗝𝗔 𝗟𝗔𝗜𝗬𝗘, 𝗡𝗜𝗡𝗨 𝗞𝗜 𝗪Ọ𝗡 𝗧𝗜 𝗥𝗔 𝗞𝗔𝗟Ẹ 𝗙𝗨𝗡 Ọ 𝗧𝗔𝗕𝗜 𝗞𝗜 𝗢 Ṣ𝗘 𝗪𝗜𝗣𝗘 𝗜𝗪Ọ 𝗟𝗢 𝗠𝗔𝗔 𝗡𝗔𝗝𝗔 𝗥Ẹ.
Superst**ion ni Eléyìí lọdọ Aláìmọkan m'ọkan Ẹda tí Yíò síi máa ṣe Àpèjúwe ọpọ Alasunmo tí O nto irú ọnà Yìí ṣugbọn ti òun dára jù wọn lọ. Kò mọ wípé gbogbo ọnà ti wọn fi dá jù oun lọ nínú Emi, Awọn ti wọn nba pàdé ni kò ì ní ìmọ itosona ti o kunna tó ti wọn fi ndi ẹni Àbuku níwájú irú wọn. Ọpọlọpọ Ẹlòmíràn síi ní o njere itona mimọ Aiyé rẹ, ṣugbọn ti wọn kunna igbese fun Aseyori Wọn. Rántí wípé Ọja l'aiye, Ohùn tí Ì bára nínú rẹ ní O maa lo kii ṣe ní Ọfẹ.
𝗡𝗜𝗡𝗨 𝗜ṢẸ𝗠𝗜 𝗢𝗚𝗢 RẸ 𝗡𝗜 𝗜𝗟É 𝗥Ẹ
Pupọ Ènìyàn Ni ko mọ wipe Ogún ti O nfi Ogo ohun Rare kìí ṣe lọwọ Ajẹ tàbí Oṣo, ṣugbọn inu ile ti O ngbe.
Ò𝗛𝗨𝗡 𝗠Ẹ𝗧𝗔 𝗟𝗘È 𝗧Ú𝗡 𝗔𝗜𝗬É 𝗥Ẹ Ṣ𝗘 𝗕ẸẸ 𝗡ÁÀ 𝗡𝗜 𝗢 𝗧𝗨𝗡 𝗟𝗘𝗘 𝗕𝗔𝗝Ẹ.
Òhun náà ni
1° 𝗔𝗹𝗮𝗯𝗮ṣ𝗲
2° 𝗔𝗴𝗯𝗲𝗴𝗯𝗲.
3° 𝗘𝗲𝗹𝗼 𝗶𝘀𝗲𝗺𝗶 𝗿𝗲.
𝗔𝗟𝗔𝗕𝗔𝗦𝗘.
Ọrẹ, Alabagbe, Iyawo tabi Ọkọ, Ọluba da iṣẹ pọ Ati Awọn Oṣiṣẹ Ẹni lee ṣe iṣẹmi rẹ lóore bẹẹ náà ni o lee yii padà kúrò ní ire. Bi Ẹdá ba si Ẹsẹ gbe ninu Awọn iṣẹmi yìí, Ọ lee máa wo O bóyá Aiye nṣe ohùn ṣugbọn Òkùnfà ti o fa tí Àgbàrá Aburú fi rán ní Agbègbè rẹ. Ni Ẹda ṣe máa nbeere ọna ki O too tọ Ọ lọdọ awọn Amòye.
𝗔𝗚𝗕𝗘𝗚𝗕𝗘.
Agbègbè ní Ipa Nlá ti O Tobi nínú Aiye Ẹni púpọ. Ọpọlọpọ lo nra ti O síi jẹ kí O ti máa fa Awọn Ẹdá míràn gòkè, ṣugbọn ile tabi Àdúgbò rẹ takò Ìṣẹ̀dá Rẹ.
Bi Arákùnrin bi Ọdún Meji sẹyìn lórí Group WhatsApp ti A ṣe idanilẹkọ nípa Agbègbè. Ọrọ wa de Orí eleyii. Ọ wa nsalaye nípa ọpọlọpọ ìdààmú ti ohùn ti ṣe lórí Àiyé ohun ṣugbọn ti o nja si pabo ni torí Ogun Jankariwo tí yio maa ba òun já kiri t**i kan inú yára ti oun ba joko sórí Àga ti Jankariwo síi máa bo oun mọ Aaye naa. Ọjọ náà lo wa nṣe ìbéèrè wípé njẹ Àdúgbò tí òun ngbe ní. Bẹẹ síi ní ti o fi mùú kúrò láàyè náà ti Ohùn tí o ti lo ọpọlọpọ oògùn sí ti ko lọ, ti O síi poora lẹsẹkẹsẹ.
Ma ṣe si Ọrọ mí gbọ wipe Ogún Aini itẹsiwaju rẹ leè jẹ Ile ti o nwọ ìṣẹ̀dá rẹ sun sí. Àṣẹdá ni itona, ọ dára kí o béèrè nípa iṣẹmi rẹ.
𝗘𝗘𝗟𝗢 𝗜𝗦𝗘𝗠𝗜 𝗥𝗘.
Aṣọ Wiwọ, Ounjẹ jíjẹ, Àsìkò fún ìgbésẹ lórí Oríire, Awọn Irufẹ iṣẹmi Ènìyàn ti o leè ba ṣe fún Nnkan kọọkan. Èso Ni Adam jẹ nínú Ọgbà Eden ti o fi bọ kúrò nínú Ọla. Bẹẹ síi Ni Awọn Ènìyàn Nuuha di Ọta fún ti O fi kàn Iyawo rẹ ni torí iwọ ni ìlú náà fún. Aṣọ ti Ì rẹwa lójú Joseph ni O padà sí itona Ti O fi di ẹru. Ìlú tí A ti bi Jéésù Ni Àtakò àti ikú tí dìde síi láti ikoko. Ọlọhun kìí ṣe Aṣiṣe, ṣugbọn Ọmọ Ènìyàn ni ko Yee. Gbogbo Ẹda lónì Ohun ti o dára tàbí Aidara pẹlu. Ogo jẹ Ohùn tí O fẹlẹ ti O fi jẹ wípé tí Ẹda ko ba mọ Ọ to, o leè sọ A dámọ̀ Ògo rẹ nu tàbí jẹ iwọ. Asise Ọjọ kan péré leè mú kí Ògo bajẹ, Ṣugbọn Yíò máa lérò wípé Ọlọhun ní O nṣe òun ni. Awọn Pupọ Ẹlòmíràn ní ko mọ Awọn ohùn Eewọ rẹ. Pàtàkì fun Awọn ti Wọn máa nlo Date Of Birth tàbí Horoscope láti fi tó iṣẹmi Aiye rẹ. Gbogbo ohun ti A fi sínú Àiyé Rẹ kọọkan lo Ni Ẹmi ti A Yan sibẹ. Ẹmi Yìí kọọkan síi ni O ní Àṣẹ ti O mba darí. Ẹlòmíràn le máa lo ina, ki Iyepe síi jẹ Ile ọla rẹ. Ṣugbọn ni torí wípé Púpọ Awọn Òní mimọ nípa Àgbàrá Ìmọ Ẹda ko tẹ síwájú láti mọ síi lọdọ Awọn Ọjọgbọn, ni àwọn Ènìyàn ṣe npadà daba wípé njẹ Òdodo ni, torí wọn kò rí déédé ohun ti wọn nfẹ.
TI O BA FẸ DI ỌLỌLÁ DI ÀLẸ, AWỌN NNKAN WỌNYI PÀTÀKÌ
Mọ Ará Rẹ Lekun ki O síi sọ Eewọ rẹ ni ti pàtàkì jùlọ
Àsìkò kọọkan wà tí Ẹda Ajé máa nwa tàbí tí Ẹda máa njade lọ bàa. Igba fífún àti ìgba gbígba.
Awọn Alaimọkan yíò máa sọ wípé Superst**ion láwọn Eleyii ti síi ṣe wípé láti Àrà rẹ Ni Pupọ Olówó tó nfi Ọlá pitan tàbí tí Òòrè rẹ ndikun láti Aimọ Ọna ti Ènìyàn kọọkan fi máa ndari Ògo rẹ.
Má máa dá Ẹnu dúró láàyè Yìí nà.
ORÍIRE RẸ KI O MA ṢE DIKUN;
ÒGO RẸ KI O MA ṢE PARUN;
ỌLA RẸ KI O MA ṢE DI A PADÀ SABURU