Ashiri Lilo Ewe Ati Egbo

Ashiri Lilo Ewe Ati Egbo IKORODU

OGUN EJE RURU ( HYPERTENSION)A o lo toju omi ti won fi se iyeree iru to won ma ndanu, so gba igo meta, alunosa ayu, AO g...
02/01/2026

OGUN EJE RURU ( HYPERTENSION)

A o lo toju omi ti won fi se iyeree iru to won ma ndanu, so gba igo meta, alunosa ayu, AO ge alunosa NAA si mejimeji, AO WA da sinu omi egbo akogun, AO ko sinu galonu kan, ao wa deepa ti o BA di ojo karun ao ma mu idaji kobu laro ati lale.

If you need any explanation on it chat me directly on WhatsApp.

02/01/2026

Aku Odun tuntun

IBUKUN AIRO TELEKa samu119 ni igba mokanlelogun(21x) si inu omi ti owa ninu ikoko ki ofi lofinda DIVINE GRACE si ki osi ...
30/09/2021

IBUKUN AIRO TELE

Ka samu119 ni igba mokanlelogun(21x) si inu omi ti owa ninu ikoko ki ofi lofinda DIVINE GRACE si ki osi gbadure pe Oluwa Olorun oba ti se ohun iyanu ni igba ti eda ko ro okan rara, Jo wo jeki ba ibukun re pade ni ona ara iyanu nipase oruko mimo re tin je AKEMO-KEHU-JAH-ZERRO-ZERRO-YE. SELA.

29/09/2021

BU IYO SOWO KO TO GBA ADUARE YII:- Agbe ni gbere pade olokun,mon gbere pade olokun mon, wagbere pade min, Aluko dodo nii gbere pade olosa mon gbere pade olosa mon,wagbere pade min, Odidere nii gbere pade oluwo mon gbere pade oluwo mon, wa gbere pade min, Akii ridi okun, Akii ridi osa, Ki omo araiye mon ridi min, Eewo ni enikan kii ridi omonigedegede, Ewe jin loni ki won oman wa fi ire gbogbo jin min,ati ile atona laafi jin olongbo, otua meji ooo, lore ture temin wa o,ire mi tin be lowo okunrin ati eyi tin be lowo obinrin ki won o wa magbe fun min o. ASE ODUMARE. (KI AWA LA IYO NA)

28/09/2021

OGUN DIABETES

Ewe olojongbodu pupo, ao gun, ao wa fi omi re, ao fi iyo die si, lilo-mimu lee meta lojumo. (ODAJU O).

FUN IWO TI O TA OJA LORI AFEFE(ONLINE)TI OSI FE RI ANU OLORUN GBA Ra igo lofinda bintu meji,lofinda onala kekere kan,omi...
28/09/2021

FUN IWO TI O TA OJA LORI AFEFE(ONLINE)
TI OSI FE RI ANU OLORUN GBA

Ra igo lofinda bintu meji,lofinda onala kekere kan,omi okun die,ki owa fi owo tuntun tele ike ti ofi se ise na,ki owa da lofinda bintu meje ji si,ki osi da lofinda onala yen na si,ki owa fi omi okun yen sinu re,tan imole kan si waju ise yii,ki osi ka samu 126 si ni igba meta,leyin ti imole bati jo tan,kio ma fi para die-die.

28/09/2021

OGUN TI OMO BA JOKO SI INU
ALABOYUN
Eja ojiji aiye kan,kuluso meje, ewo apadi meje, iru, iyere, iyo, epo, ao fi se obe aseje.(ODAJU O)

28/09/2021

Any spiritual help contact me on WhatsApp

Address

Lagos

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ashiri Lilo Ewe Ati Egbo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share