27/02/2024
AMOJUTO FUN GBOGBO IRAWO FUN ONA ATILA ATI RIRESE WON KIAKIA PELU IMO ASTRONOMY ( ORUKO) ATI ASTROLOGY ( OSU).....
Pelu imo astronomy ( oruko) ATI astrology ( osu), lafin ma ona asiki,ATI ije imu, ATI ona atila NI olohun ko ma iseda kokan lati tete be GBE PE...
Awon IRAWO (ADAMO) afefe; won pin SI ona meta: BURUJI Gemini ( afefe ALAWADA), BURUJI Libra ( afefe MARIMIFIN), BURUJI Aquarius ( afefe ONIBINU), awon irawo irawo afefe yi, won ma Saba feran iriajo, won SI Saba ma feran lati soro tabi koyan maran pelu eni tiwon ba feran, ibikibi TI won bawa nma dun, won ma feran awada ATI ikoyan mara, won ma feran lati se nkan toma yato SI telo Miran, won Saba NI ifarada nigbati wahala kan bade, won ma Saba fi ikanju see nkan, to je pe, TI won ko bati see ikan tan, won tun ma see imi, ikan yen sima pawon Lara PUPO lati tete se aseyori, won ki ma owo kan lai na, suru won ki Saba pe pupo ra, AFI TI won koba fe soro, Tori won ki Saba RI Oro GBE SI emi won, won ki Saba di yan sinu, won ma Saba to pinpin nkan pupo, won Saba gbara le yan gan, won ma tete binu si nkan TI pa pawon Lara,...
Ogun dudu ki Saba sise Lara won, Tori iseda won Kori ra re PUPO, sugbon pelu adua ATI oruko olohun to ba ISEDA won mu ati Sara to ba ISEDA irawo yi kokan mu, nijo tiwon bati she, NI ayipada, ATI oun rere, yo TI ma sele sinu aye won Kia Kia,..... WALLAHU A'LAM...
GBOGBO ENI TOBA SHARE RE, FUN AFANI ELO MI, AO NI WA AYE ASAN OOO
OLOHUN YO FIWA MANA...
BY AR-RAZAQIY INTERNATIONAL
WhatsApp number or call
08105428760