Oluwa loni iwosan ede

Oluwa loni iwosan ede Orile Coker road

18/01/2020

ASIRI YI DARA FUN GBO WA LATI MON LO
Kosi eniti koleelo
Okere loju sugbon
Hummmmmmmm!!!
ni enu ise kisekise ti aba NSE
A o Mon di aayo ni enu ise naa

Ise naa in yii

Ewe iyalode funfun
Ewe iyalode pupa
A o gun mo ose any of our choice
A o wa ko si inu ike pure
White kan
A o wa gbe ose yi tiketike
Si inu oorun ago kan
A o wa fi ori shearbutter si
Ose yii lori
Toba to yo daada
A o wa fi owo hand poo papo
A o Mon fi we
Tested OK.

17/12/2019

ASEJE TI O NFA #25,000 WA

Oga gbigbe tope kan, ewe aluki, iyere 25, ewe abamoda, sawerepepe, ewe ola die ati ikoko aseje tuntun kan.

SISE RE:-a o lo lotooto, a o wa da sinu ikoko aseje tuntun kan nikookan, a o fi iru ati ogiri ijebu si, a o fi epo ati iyo si, a o wa se laseje, ti o ba jinna tan, a o so sori osuka, leyin eyi a o wa pe ofo re si.

OFO RE:-aba ti alagemo ba da ni orisa oke ngba, abamoda ki i da tie ko ma se, ki emi lagbaja omo lagbaja ri egberun medogbon naira ni kiakia.

JIJE RE:-leyin ofo re a o wa je aseje na.

N:B-gbogbo ewe yi gbodo je tutu ti oojo atipe eniti o ba fe se ise yi gbodo je eniti ogun nsise lara re.

Iwo ti o ba fe ki o je fun o, ki o so pe osi oni mo ile emi ati gbogbo omo egbe

03/12/2019

DO NOT DIE IN SILENCE,
DO IT YOURSELF.

1. ENGLISH: TYPHOID FEVER (1)
Take Alabukun with lime water, squeeze ugu vegetable into a glass cup with two local eggs, half tin milk and two spoons of natural honey mix together and drink it. Three times a day after meal.

YORUBA: IBA JEDOJEDO (1)
E lo Alabukun pelu omi osan wewe, egbo efo igu sinu cup kan,eyin adie ibile meji, idaji agolo miliki ati sibi oyin igan meji, e po papapo ki e si gbemu. Emeta loojumo leyin ounje.

2. ENGLISH: TYPHOID FEVER (2)
Ten lime oranges (H20) mixed with garlic and three teaspoons of original honey should be used morning & night after meal.

YORUBA: IBA JEDOJEDO (2)
E fun osan wewe mewa,lo ayu(garlic) si, pelu sibi oyin igan meta. Eloo leemeji lojumo aaro ati ale.

3. ENGLISH: TYPHOID FEVER (3)
Get unripe pawpaw, unripe pineapple, ginger, lime orange, sugarcane and Lipton tea 2sachet.Cut everything into Pieces and boil them with fermented corn water(omidun) for one hour+. Take one glass cup 3 times daily for one week with original honey mix together.

YORUBA: IBA JEDOJEDO (3)
E wa ipepe ati ope oyinbo dudu, atale, osan wewe, ireke ati lipton tea meji. E ge gbogbo awon eso wonyi, ki e si fi omidun se e fun wakati kan ati die. E ma mu ife kan ni eemata ni ojojumo pelu oyin igan die ninu e fun ose kan.

4. ENGLISH: EZEMA/RING WORM
Mix some native soap with grounded potash, add lime orange to it and apply the mixture on the spot after bathe.

YORUBA: IFO/EELA
E mu ose dudu ibile, koun ti a nfi nsebe ati omi osan wewe, e po gbogbo e papo ki e fi ma pa oju e.

5. ENGLISH: HYNEA
Get some leavesof casia alata, boil with water and drink one glass cup daily.

YORUBA: IPAKE
E mu ewe panseke ki e se pelu omi ti o mo ki e fi oyin igan die si. E ma mu ife kan ni ojojumo.

6. ENGLISH: INTERNAL HEAT
Get some quantity of dry pawpaw and cashew leaves. Boil with water and drink 1 cup 2 times daily.

YORUBA: ORU INU
Ewe ipepe ati ewe kasu ti o ti gbe daada. E se ki e ma mu ife(cup) ni emeji ni ojujumo.

7. ENGLISH: NATURAL FAMILY PLANING
Get some root of cashew tree, boil and add original honey to it. Take one cup per day after monthly period for one week before making love.

8. ENGLISH: JAUNDICE PAIN
Get the water of unripe pineapple, three lime oranges, and three ijagaun orange, mix them together. Four spoons 3 times a day after meal.

YORUBA: AWOKA ARA
Fun omi ope oyinbo ti kopon, pelu osan wewe meta, osan ijagaun meta papo, sibi merin, eemeta lijumo leyin ounje.

9. ENGLISH: A**S PULLING OUT (1)
Tetracycline (6) mixes with original honey 2 spoons. Rub the a**s with the solution when it pulls out.

YORUBA: IDI YIYO (1)
E po tetracycline (6) pelu sibi oyin igan meji.
E maa fira idi na ti o ba tiyo.

10. ENGLISH: ULCER (1)
Use three spoons of original honey with pap early in the morning before meal for 6 days.

YORUBA: OGBE INU (1)
A o fi sibi oyin igan meta fo eko mu laaro ki a to jeun fun ojo mefa.

11. ENGLISH: ULCER (2)
Squeeze either pineapple or pawpaw seed to produce water and filter it. Mix the solution with tin milk and drink it for seven days.

YORUBA: OGBE INU (2)
A o gbo pineapple tabi eso ibepe a o se. A o po agolo milk kan mo. A o si mu fun ojo meje.

12. ENGLISH: ULCER (3)
Get 8 unripe plantains, peel them and cut them into pieces and pound them to paste. Pack everything into a container (1 five litters gallon), fill the gallon with drinkable water add little honey. Allow to ferment for 3-5days and take one cup 2 times a day.

YORUBA: OGBE INU (3)
E mu ogede agbagba dudu mejo, e bo lara ki si rin dada ni tutu. leyin eyi, e ko sinu galonu kan ti e ti pese sile, e ro omi mimu sinu e pelu oyin igan die e file fun ojo meta ki o toro dada. E ma mu ife(cup) meji leemeji lojumo.

13. ENGLISH: TOOTH MUCH FAT (OBESITY)
Peel the back of maize, lime orange and cook them with water. One tumbler 3 times daily.

YORUBA: ARA SISAN JU
Eepo eyin agbado, osan wewe, a o se pelu omi lasan. 1 tumbler emeta lojumo.

14. ENGLISH: SLEEPLESS NIGHT(1)
Undiluted honey, aloe Vera juice mixed together, take two or 3 spoons every day.

YORUBA: AIRI ORUN SUN DAADA (1)
Ogidi oyin ilarin coke, oje ewe eti erin (aloe vera), a o da papo, sibi metameta lojojumo.


15. ENGLISH: SLEEPLESS NIGHT (2)
Add(2) 3 spoons of honey into glass cup of milk(low in cholesterol).Take all as soon as you are ready to go to bed.

YORUBA: AIRI ORUN SUN DAADA (2)
E da sibi oyin igan gidi meta sinu ife miliki kan, ki esi mu ni ale ti e ba ti fe sun.

16. ENGLISH: WEAKNESS OF THE BODY
Cut aloe Vera into cup, put water for 5 minutes and drink the liquid.

17. ENGLISH: THROAT PROBLEM
A handful of Abeere seed, grind it well and mix it with honey (half coke bottle).One spoon every hour.

YORUBA: BELUBELU
A o lo eso abeere ekunwo kan kunna, a o fi sinu oyin igan idaji igo coke. Sibi kan wakati kan.

18. ENGLISH: CIRCUMCISION/SCAR ON NEW BORN BABY MANHOOD
Mix groundnut oil and goya oil, original honey ¼ coke bottle, use it to rub it with cotton wool.2 times a day.

YORUBA: OGBE ATI ITOJU OMO TI A DAKO FUN
Ororo epa, Ororo goya, ilarin oyin igan, a o dapo a o ma fira ogbe naa leyin fifo, a o fi owu otutu si oju re. Emeji lojumo.

19. ENGLISH: DIABETES
Bitter leaf, scent leaf, squeeze them, add little potash, grind 3 bulb of onion garlic and mix it with the solution above. Also squeeze dongoyaro leaf with the solution. Adult: 3 spoons 3 times a day; children 1 spoon 3 times a day.

YORUBA: ITO SUGAR
E gbo ewuro, efinrin, dongoyaro papo ki e se omi re, e fi kaun die si, e lo ayu, alubosa elewe meta da sinu e. Agba sibi meta eemeta ojumo; omode sibi kan emeta ojumo.

20 ENGLISH: ASTHMA
Take the fluid of the snail and mix it with the original honey till it becomes light 3 spoons 3 times a day.

YORUBA: IKO EGBE
A o po omi inu igbin po mo oyin ti yio fi san. Sibi meta lemeta ojumo.

21. ENGLISH: TEETHING PROBLEM(1)
Some alum, some potash, a spoon of salt, native pepper. Grind them together put small of it to the affected teeth and wash your mouth with lime water after 5 minutes.

YORUBA: AKOKORO (1)
E o lo alomu die, kaun bilala die, iyo sibi kan ati atale die papo. E o bu die si awon eyin naa. Leyin iseju marun fo enu pelu omi osan wewe.

22. ENGLISH: TEETHING PROBLEM (2)
Get a mixture of lime orange juice and honey (equal quantity) 1 teaspoon 3 times daily.

YORUBA: AKOKORO (2)
E da oyin ati omi osan wewe papo(iwon kanana) ki e si ma fun omo naa ni sibi omode kan ni emeta lojumo.

23. ENGLISH: HEAR PROBLEM
Drop Bintu Perfume inside the ear and cover it with cotton wool. (IT’S ABOMINATION FOR TWINS).

YORUBA: ETI DITUN
A o ma kan lofinda Bintu si inu eti naa a o si ma fi owu otutu sii. (EEWO NI FUN IBEJI).

24. ENGLISH: WEAKNESS OF MANHOOD
Cook 21 pieces of onion and squeeze the juice into a container.One spoon 3 times every day.

YORUBA: NNKAN OMOKUNRIN TI KO LE DARADARA
E ge alubosa onisu (21) ki e fun omi re sinu igo kan fun lilo. Sibi kan lemeta ojumo nigba gbogbo.

25. ENGLISH: WEAK ER****ON
Get plenty of white onion, grind and extract the juice, mix with equal quantity of honey. Take 2 spoons of it three times daily.

YORUBA: OGUN ALE
Emu alubosa funfun ki e si loo kunna daada. E fun omi inu re jade ki e si po po mo oyin igan gidi. E ma mu sibi meji meji leemata loojumo.

26. ENGLISH: HYPERTENSION
Take two spoons of original honey before eating (morning & night).

YORUBA: EJE RIRU
Mu sibi oyin igan gidi mejimeji ki a to jeun aaro ati ale.

27. ENGLISH: SEVERE HEADACHE
Squeeze scent leaves and rub the juice on your forehead every day.

YORUBA: ORI FIFO
A o gbo efinrin a o ma fi omi re pa iwaju ori lojoojumo.

28. ENGLISH: SEVERE COUGH (1)
Grind some bitter cola (10) and mix it with original honey. Adult: 3 spoons, children: 1 spoon 3 times a day.

YORUBA: IKO KEHE (1)
A o lo orogbo mewa a o da sinu oyin igan. Agbalagba: sibi 3, omode: sibi kan lemeta ojumo.

29. ENGLISH: SEVERE COUGH (2)
¼ honey, lime water, ¼ palm oil, mix together. A glass cup 3 times a day (adult) two spoons 3 times a day (children).

YORUBA: IKO KEHE (2)
Oyin gidi ilarin, omi osan wewe ilarin, epo pupa ilarin, a o dapo. Agbaagba: 1 glass cup, Omode sibi meji lemeta lojumo.

30. ENGLISH: FREQUENT STOOLING OR DYSENTRY
Take a glass cup of your early morning urine.

YORUBA: IGBE GBURU
Ma a mu ito ti o ba ji to ni aaro.

31. ENGLISH: PILE
Take one spoon of original honey. After an hour squeeze scent leaf and bitter leaf with lime water and filter it. 3 spoons three times a day.

YORUBA: AKO JEDIJEDI
Mu sibi oyin igan kan leyin wakati kan ki o gbo efinrin ati ewuro pelu omi osan were ko o se. Sibi meta leemeta ojumo.

32. ENGLISH: SWOLLEN LEG IN PREGNANCY
Boil corn silk with water and honey. A glass cup a day.

YORUBA: ESE WIWU NINU OYUN
A o se irukere agbado pelu omi nati oyin die a o ma mu cup kan lojumo.

33. ENGLISH: MEASLES
Grind bitter leaf and mix it with either honey or gin. Drink it and rub body with it.

YORUBA: IGBONA OMODE
A o gbo ewuro ao da papo mo oyin igan tabi oti ibile. A o ma fun omo na mu ati para fun.

34. ENGLISH: MENSTRUAL PAIN
Get Oriji herbs, wash it and cut it into pieces. Soak it with water. Drink it for 3 days before your menstruation.

YORUBA: IRORA NINU NKAN OSU
E o re egbo oriji pelu omi obinrin naa yoo mu fun ojo meta ki o to ri nkan osu re.

35. ENGLISH: MENSTRURATION PROBLEM
Get 3 wonderful cola, ginger and garlic, cut them into pieces. Get 1 bottle of lime orange juice.
Pour the three substances into the bottle of lime and add small original honey to it. Take 2 spoons 2 times a day.

YORUBA: IKAN OSU OBIRIN
E mu obi abalaye (wonderful cola) meta si marun, atale ati ayu. Ege won si wewe ki e si ko won sinu igo omi osan wewe kan ti e ti pese sile. Efi oyin igan gidi si, ki e ma u sibi meji meji ni emeji loojumo.

36. ENGLISH: LOW S***M COUNTING/WATERY S***M
Mix 3 spoons of original honey, 3 local eggs and a tin milk together and drink it twice a week.

YORUBA: ATO SISAN
A o da sibi oyin igan (3) eyin adie ibile meta ati agolo miliki kan papo; a o maa mu ni emeji lose.

37. ENGLISH: BOIL
Grind otili leaf and mix it with ori amo. Rub it on the boil.

YORUBA: EEWO
A o lo ewe otili kunna dada, a o po po mo ori amo. A o ma fi pa eewo naa.

38. ENGLISH: CHILDREN MIDDLE HEAD PAIN
Cut alubosa elewe into pieces fry palm oil on fire and add that onion and iru woro to it and leave it till the naming day of the child before star using it to rub his head.

YORUBA: OKA ORI OMODE
A o ge alubosa elewe si wewe, a o gba epo dada a o da iru woro ati alubosa elewe yen si, a o duro di ojo isomoloruko, a o da oruko omo na si a o si ma fi pa awuje omo naa.

39. ENGLISH: DANDRUFF
Grind lali leaves with alubosa elewe, dry it and re-grind it and pour it inside hair cream for usage.

YORUBA: ESIN ATI AJERUN
A o lo ewe laali po mo alubosa elewe a o sa gbe, a o si tun lo, a o da sinu iparun a o ma fi pa ori wa.

40. ENGLISH: URINATORY CHILD
Let the child be taking 2 spoons of original honey after eating at night.

YORUBA: OMO TI O NTO SILE
A o lo sibi oyin igan meji fun omo naa leyin ounje ni ale tabi sibi meji meji lojumo ko ba tete duro.

41. ENGLISH: SAFE DELIVERY
A pregnant woman should be drinking chickweed (Ewedu) soup at all time or squeeze it and be drinking the juice.

YORUBA: IBIMO ALABOYUN NI IRORUN
Alaboyun yi o mamu obe ewedu nigbogbo igba tabi ki o gbo ewedu pelu omi die, ki o si maa mu omi re.

42. ENGLISH: RASHES (1)
Mix lime water with black soap and use it to rub the affected part.

20/11/2019

.

(1) EWE LAPALAPA FUNFUN
(2) EWE AJEOBALE
(3) EWE KOJOLOTI
(4) EWE EWURO
(5) EWE KOKO
(6) EPO PUPA
(7) EPO OBO
(8) ADIN
(9) ORI

AO GUN GBOGBO RE PAPO MO OSE DUDU, AO FI EPO, ADIN, ORI PO OSE NAA, AO KO SINU IKE FUNFUN AO MAFI OSE NAA WE.

MAJEMU ISE NAA LIKE POST YI KIO SI SHARE RE SI GROUP ASIRI MIRAN TIO BAMO KIO LE JE ANFANI FUNWON, KIO SI SE AMEN ADURA SI ABE COMMENT YI, OLORUN YIO MAA RANMI LOWO.

24/10/2019

ASEJE AWURE OWO
ewe anu,atajosi mesan 9,iyere mesan 9 aolopo aofise eja alaran je aoge si meta 3 aoje.odaju.

15/10/2019

OGUN PROMISE AND FAILED TI OMO YAHOO BASHE ISEYI MOFI OLORUN BURA KOSI CLIENT TI O PROMISE E TI KONI MOSHE
Ito idaji lai soro si enikeni
Iru woro
Ose dudu
Iru woro ao lo pelu eru inu aro ni owuro kutukutu lai soro si eni kankan rara ao gun pelu ose ti oto we ni emeta ototo ...ito ti atoyi ni aofi pa gbogbo ara wa ni ati ori de ekanna ese wa ao je ki itoyi gbe mowa ni ara bi (OGUN ISEJU) leyin Ogun iseju yi aobu odakan ninu ose ti agunyi ao fiwe ni aro kutukutu lai ti soro si enikankan ni owuro ojo ti agun ose yi ao wa wole aotun webe ni osan ti aba webe aotun we ni ale ti olorun bati fuwa she ni iseyi kosi Ogun promises and failed mo ni aye re mo....
Emi oni oniso wepe odaju sugbon danwo owun ni obi iya okere 🙏🙏🙏

15/10/2019

Egun Awure Ola
Ewe kole orogba,igba atikan,ewe awerepepe, amunimuye,ori pangba amoka,eyele funfun kan,aogunpo ninu odo,opolopo ose lafi po,ako sinu awo funfun tabi ike funfun,.
Ise timo send yi,edakun mofe kefi se adura fun iyamin abike édu,ki olohun jeki eminre kogun,funmin,
Nitoripe alubarika re nimojé, ona tola kalé nimohun to.........

15/10/2019

OGUN TIWON BA GBEWA NI NKAN.
Esuru pupa, ao pani pansa ao bu adin sinu iho na ao waa depa ao
walo gbe ile ni oritameta ao gbe sinu ile na ao pe gbolohun re si.
Gbolohun;- suru-suru lan soro esuru
-eniti o jimi ni nkan ki ara bere sini nii t**i yio fi da nkan mi pada
fun emi lagbaja omo lagba (ao wa da iyepe bo lori)
AKIYESI- TOBA TI MU PADA AO LO HU NKAN TI ARIMOLE AMA
JUSI INU OMI TUTU.

15/10/2019

OGUN IGBEBI NIRORUN FUN OBINRIN TODE ORI IKUNLE TI OMO KOWA TI WON WA FE SE ISE ABE FUN HMMMMM WALAI MOFI SARE MI BURA OGUN TODAJU NI,Ao mu igo ofifo ti kosi nkankan ninu re ti osi ni ideri kan,ao wa lo wa ekolo nla toma n jade ni asiko ojo RAIN yen ao wa fi IKA wa kan lale ni iwaju ekolo yen,ao wa gbe igo yen si ibi ila tia la yen,ti ekolo yen ti yoo fi ti ori bonu igo yen,ao wa da opolopo omo atare sinu re,ao wa de IGO yen pa,ao wa so okun mon orun IGO yen,ao wa GBE ko si igun yara wa,leyin ojo keje ao ma lo,LILORE"Ao mu bi eyo atare meje pere si obinrin yen lenu yoo je,yoo wa mu omi gbigbona si,hmmmm pelu ogo olohun oju ese nani omo ati ekeji omo yoo wale,hmmmmm Iwo naa ranti mi ninu adura,

15/10/2019

Tested and confirmed ok

(_ OSE_AWURE_TODAJU)

Koko oro mi niwipe ki o mase alai dan asiri yi wo ni kiakia toriwipe bi eniyan o bale se adua oye ki ole se IGBIYAJU
Asiri ni eleyi kiise oogun nitori meji meta nani OGUN kiidun kopo soki bai ni obe oge

Ero nja re:
Egbo butuje ff ojo, Epo Obo, Eeru alamo, Ao gun po mo ose dudu ao wa ko si nu igba olomori odi wiwe ni araaro pelu aniyan
Ose yi
Osise bi orisa ibeji nio .
Meji loma'hun rin

2,
OSE ANU RE NI ELEYI

Ogiri, Aasa tiwon ma'nfin, Ao lo pelu Ose dd omi agbon ni ao fi po
Ao gbodo je ninu agbon yen ao fi se Sara ni tabi ki eso agbon yen nu. Ao ko Ose yen sinu ike ff,

Ose na di wewe laro laro.

😀 Sowipe 😁
👇👇👇

09/08/2019
05/08/2019

Instead of those sleeping pills for Insomnia, why not boil a whole banana and drink the water. (Natural remedy)

If you are having difficulty sleeping, restless nights of tossing and turning, staring at the ceiling, unable to get more than a couple hours of sleep with boiled banana you not only gonna sleep but also enjoy sweet dreams.

This tea takes less than 10 minutes to prepare and can be enjoyed every night before bed.

Ingredients:
1 organic banana
1 small pot of water...
cut off both ends of the banana and place it, don't remove the back,just slice into boiling water. Boil it for around 10 minutes. Next: pour the water into a mug.(sprinkle cinnamon into the tea: ).
Drink it one hour before bed time.

This organic, banana-infused sleep remedy works wonders and tastes so good. How does it work? Bananas, especially the peels, are loaded with potassium and magnesium. While magnesium helps prevent sleep disturbances, both magnesium and potassium work together to help relax muscles. In fact, magnesium is one of the best minerals for relaxation! Keep in mind, this recipe calls for 100% organic bananas. Bananas that are not organic are loaded with harmful pesticides and since we encourage you to eat the boiled peel, it must be chemical-free.
This tea takes less than 10 minutes to prepare and can be enjoyed every night before bed.

05/08/2019

HEALTH BENEFITS OF STUBBORN GRASS

Botanical name : Sida Acuta
Isekotu in Yoruba language.

* For bacteria in the body system,severe waist pain, ankle pain,lower abdominal pain during me**es, hormonal imbalance,irregular me**es,watery s***m and quick ej*******on.
This dreaded disease refer as rheumatoid arthritis which normally develope sympthons like; deformation, joint pain, swollen ankle, and general inflammation of body.
Infact do ctors and scientists have not figured out the real cause of this disease, but it is believe to be caused by polluted environment, smoking, life style, and genetic factors., eventhough our body normally form antibodies that fight virus and diseases.
It is a specialist in decreasing life expectancy, which have left many on the wheelchair and cause some people to look older and subjected to early death.
Today in Africa, a lot of people who often experience deformation and have their swollen ankle left with punch-hole, often keep malice with their suspected family members and neighbors as an architect to their problem, due to ignorant and mental slavery.
Here is a wonderful plant that God has deposited to help us in perfect treatment of this dreaded disease, but it required to work only if you reserve the rule and perfect preparation.
This plant is to be harvest early morning hour of 6:00 am dot before before the sunset, if not it won't perform, and must be kept in cool in cool or wet place if you aren't ready for immediate preparation.
Get 2 big balls of white onions ready, harvest three handful of this plant and wash it with water and salt.
Then cut in pieces and pour 4 liters of fresh water in a pot, cut the two balls of white onions and spray it on the top.
Boil it for maximun of 15 minute and filter the water for your healing. drink a glass for morning and night to testify of goodness of God!
general weakness: boil only the leaf and drink one glassful thrice daily
kidney problem: fill a medium size pot with the root and water. Bring to boil. Half glass twice daily
insomnia: add almond and bamboo leaves to sida acuta leaf with it. Bring to boil one glass full twice daily

* Uproot the plant 6.00 am on the dot. Wash the soil of the root and leaves. Boil it a little and drink. It works for Arthritic pains.
Squeeze the leaves with ordinary water. It draws. Drink it first thing in the morning and last thing at night for Ulcer. Use it with young Guava leaves for more effectiveness. Thsnk me later

* It's use in treating infection (urinary track infections) diseases. Boil it very well, pour it into a cup, add 3 spoons of dust/ash fire wood, e.g in the village, fire wood is used in cooking, the dust or ash you may call it, is what I refers to, mix it together, filter it and drink a cup of it warm for 7 days, morning and evening

* Good to treat back pain.
Quantity of it with pineapple leaves.Boil it together and drink It cure athrites and back pain

* When ur wife find it very hard to give birth , try and grind it with some salty dried finish and mix it little with water and let her drink it. If she no deliver the baby at home then God no dey

* it is use for sturbon boil. Grand and rub around the boil .

05/08/2019

TREATMENT OF ASTHMAH WITH HERBAL
This is a condition in which person airways inflamed narrow and swell to produce extra mucus,
Difficulty to inhaled normally occurred,
The herbal treatments are
1.six bilitter kolla
2.blue alum
3.ginger
4.garlic
Soak six kola into a plastic bottle for four days add blended ginger and garlic and blue alum for four days
Take a tot of gin early morning before food,you will vomit mucus that block the airways.

22/07/2019

HEMORRHOIDS TREATMENT ON HERBAL METHODS,
This is swollen and inflamed veins in the re**um and a**s that causes discomfort and bleeding from the a**s and also called pile,
These are the herbal ingredients and methods of application,
Fresh teteregun leaves and unripe fresh plantain with fresh asuwon leaves cut both into pieces into a 2litres keg add a clean water and leave to ferment for 48 hrs,
To be taken a small glass cup every morning before food and every nite before bed.

22/07/2019

ERECTILE DYSFUNCTION HERBAL TREATMENT,
This is when a man can not get or have an er****on firm enough for s*xual intercourse,also an ability to get and keep an er****on firm enough for s*x,
Many health problem can cause er****on dysfunction, which could be medical problem, mostly diabetes or health conditions, to***co smoking can restrict blood flow to veins and arteries also chronic health conditions can cause it,
Before taken any drug go for laboratory test to confirm medical conclusion,
Homonal imbalance are major causes of erectile dysfunction,
Here are the herbal ingredients for homonal imbalance,
Pear fresh leaves
Fruit dried leaves (fallen)
Lapalapa roots (white)
Ginger (white and red)
Honey
Boil all together for 30 minutes add honey to taste,
To be taken a full glass cup every morning and nite after food for one week,
Soak a male pawpaw root into à plastic bottle with original gin,
To be taken every nite before bed after food.

14/05/2019

Address

Lagos

Telephone

+2348187723696

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Oluwa loni iwosan ede posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Oluwa loni iwosan ede:

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram