02/07/2023
DIE NINU IWULO EWE EWURO..
1, OSE IFOWO FUN YAHOO BOYS,
ewe ewuro die, eepo obo die, gbogb ifun inu ako Alangba Ao gun papo mon ose dudu, Ao ma fi fowo ti aba bere sini ba client wa soro... Omi Aye ni ao fise omi re.. Odaju pupo...tori Àlàmú kimu nkan tii....
2 AWURE ASINA ITAJA FUN ENITI OJA RE KOTA.
ao jii ni owuro kutu kutu lai tii kii eeyan kankan, Ao lo ja ewe ewuro, ao gun mon eepo obo die, ao gun mose dudu, ao kosinu ike ff, ao ma we lararo kia to lo ibi oro AJE wa, ODAJU
3.AWURE OWO TI ABA FI WE OMO TUNTUN AO RII IYALAYA OWO LOJO NA,
omunu ewe Ewuro Ao ja ao gun mon Kafura pelebe eyo marun, ao gun mose dudu, ao ko sinu ike funfun,
Ao ma we laro laro..
4, TI WON BA DA OKUTA ABI AGBANA SIBI ORO AJE ENIYAN, ABI OOGUN OSISE LARA TAARA,
Ao ja ewe ewuro, a o fi omi lasan gbo, Ao yo omi na, ao fii won ile ibi tiwon da okuta na sii, Ao tun fi omi yi we
Pelu ogo olodumare Aje yi o wa....
5. OKIGBE (ANTICUTLASS)
Ao Ja ewe Ewuro yio po die, Ao ko ORUKA KUNSANRIN MERIN4, Ao te ewe ewuro sile ninu Ape ijogun wa, Ao ko iroka sii lori pelu atare nla kan sii, Ao wa da ewe ewuro toku bo lori, Ao jo papo,
Ti aba jotan ao ko iroka yen kuro, Ao fi Ebu ijogun yen si igbere meta3 meta3 sii orikerike wa, ao ma fii Iroka na si owo
..
6.. KI OGUN MALE RAN ENIYAN, (BACK TO SNEDER)
Ao ja Ewe Ewuro yi o po die, Ao ko die tele Ape ijogun wa Ao fii Oga gbigbe kan silori, Ao fii atare aaja kan si legbe, Ao ko ewe ewuro toku bo lori, Ao Jo papo,
Lilore
Ao ma fii Ebu ijogun se isu je, Lai bu omi sii tia ba fe see isu yii, ao gbudo bu omi si o, Ebu ogun yi lasan lao busi, Yio jina,..
Opo eeyan le je isu yii...
Walai Kosi Asasi yen koni ranwa..
Fun ibere tabi ohunkoun pe 07054043497