Awon Ogun iwosan Ara

Awon Ogun iwosan Ara Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Awon Ogun iwosan Ara, Drug Addiction Treatment Center, kwra ilorin, Oyo.

EYONU AWON AGBA JENRI AYEGBEise yii kere loju nio but ise nla ni fun eniti obada nkan mo gbogbo eniyan lole lo agaga eyi...
14/01/2026

EYONU AWON AGBA JENRI AYEGBE

ise yii kere loju nio but ise nla ni fun eniti obada nkan mo gbogbo eniyan lole lo agaga eyin tewa ni Lagos State mowo sakun bii ise yii tima n sise oba ọdọ yin mu gan ni kosi ilu tawa ti akole loo emi kan so temi nio

ISE NA LO BAYI
ori agutan tutu kan eyin ororo mokanle logun afara oyin topo die odidi atare kan aofi ori yen tele ape aoko awon eyin yen yipo re aowada afara oyin yen bo mole aofi odidi atere kan si aowa fi iye awon agba funfun meji tele inu sere nla kan ibe ni ama da etu ifa yii si aoma fifo eko mu lemeta losu kokan. idi sere yen kogodo kale o ama soko soke nio

ipeayo herbalist services whatsapp only 08067248932.

EYONU OSHOLE TI AFI NYANJU ORO IGBESI AYE ENIIIse yii kosi fun oponu eniyan oOwa fun eniti ọ̀rọ̀ aye re baka lara nikan ...
08/01/2026

EYONU OSHOLE TI AFI NYANJU ORO IGBESI AYE ENII

Ise yii kosi fun oponu eniyan o
Owa fun eniti ọ̀rọ̀ aye re baka lara nikan awa ti aba fese ejeki a dm awati abasi fegba gbohun re taje aji jawe aji wa egbe ise ti ama san ẹ̀jẹ̀ le lori ni ejeki awa na dm
Mofi Olódùmarè bura lori ise hmmm ise nla nio asiri inu ile sini pelu
O sare mu arisiki wa pupọ

Ise na lo báyìí
Eku asin tutu kan eso ido 201 werenjeje 201 ewe aluki ni won ba ata ijosi topon si ori igi rẹ eyo 9 ekuro ifa ti won ti bọ 1 abo adire dudu toje agbebo kokoro ikamudun lọpọlọpọ aopa adire yii aofi obe tuntun kan la igba aya rẹ aofi Eku asin tẹ́lẹ̀ inu adire yen aoko awon nkan toku le lori note kokoro yen lao da sori nkan yen last o aowa pa igbaya re de mo awon nkan tati ko sinu re yen aowa da aya adire yii denu agbada ti afefi jo yoko eyin soke ao wafi ọwọ kan odidi igbale kan di kekeke aowa da sori adire yen ninu ape towa tati fe jo ofi jijo tobajo tan aolo aoda sinu akere ngbe kekere kan ao wa pa àkùkọ adire kan fibo ise yii aole irun aya adire yen mo lara ao malo ise yii ni ale pelu gbólóhùn rẹ
Fun awa ti aba nifesi atise ejeki a dm awati abadife gba gbólóhùn rẹ ti aje onisegun kawa na dm but kise ofe ni gbigba gbólóhùn rẹ o tori kise ise ọpọ eniyan rara
Ipeayo herbalist services whatsapp only 08067248932

IMULE TOTUN SISE OSOLE ORO ISAJU ** somo idi ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ise ori Facebook kifi saba sise fun ọpọ eniyan *alakoko ero p...
29/12/2025

IMULE TOTUN SISE OSOLE

ORO ISAJU ** somo idi ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ise ori Facebook kifi saba sise fun ọpọ eniyan *alakoko ero pupo ju lori ise eyokan,
*elekeji kíkọ lati losan owo ajegun fun eniti ofi ise sile
*ele keta elomiran tofe da ọwọ le ise yen kise ise re okan se atojubo lasan ni
*elekerin lilo aye deru eroja
+elekarun aini imo toye koro lori ise tofe dawo le

note iwọ tofe dawo le ise kan tobati ka ise na toba sepe ise tomo nipa re dada ni oye koti mope oye kopada s**o eniti ofi ise yen sile boya otun leni ona kan totun ma to eh si lori ise yen or lati losan owo ajegun ise na elomiran oto ni ise to nse atun ma bawon dasi ọ̀rọ̀ ewe ategbo tobawa kowo se ogun tiko bawa sise ani ise ti won fi sile kope dakun ebi tani ejeki oni Kaluku gbajumo ise olorun firan iwo na toje ise kajawe wagbo lo nse toba se wipe ise yen ye o dada oye komope oye kopada si ọdọ enito fise sile ni lati lose eto

ise na lo báyìí
aogbe ape ka ori ina aogbe ẹyẹ kanakana sii arin ape yii ti yoko aya soke aofi ẹyẹ kowe si apa otun re aofi ẹyẹ iga akọ kan si apa osi re aofi odidi atare kan si aya kanakana yen aowa gbe ori tobato ikuku wa kan le ori atare yen mole lori kanakana yen aowa da adi dudu igokan si ati epo pupa igo kan awajo taaba jotan aoro sinu igo ff or ado aato kan aoma fi otilo lowuro
(ipeayo herbalist services whatsapp only 08067248932)

IMULE AJE ORUN TOTUN SISE OSOLE(IKILO PATAKI)gbogbo eniti kobato  40years koma gbiyanju ise yii ooo nd kise ise ti obìnr...
25/12/2025

IMULE AJE ORUN TOTUN SISE OSOLE
(IKILO PATAKI)
gbogbo eniti kobato 40years koma gbiyanju ise yii ooo nd kise ise ti obìnrin lese ooo
NOTE
akọ isẹ nla ni iṣẹ́ yii gbogbo eni toba mo nipa ewe ati egbo ni ko tẹrí si o

ise toyara sọ eyan di olooro ninu aye ni ise yiii mofi Olódùmarè bura si ise yii atari ajanaku ni kise eru omode but kosi eniti obalo isẹ yii ti ona re koni la ninu aye koda ki eniyen je olori buruku tẹ́lẹ̀ a*o di olori re (ipeayo herbalist services whatsapp only 08067248932)

ise na lo báyìí
ẹyẹ ayé koto ooye kan, ẹyẹ olongo tutu kan ẹyẹ olofere tutu kan okete tutu ti won pa loojo ewe owu akese tutu toojo ado ide nla kan odidi atare nla aofi okete yen tele ape aoko awon ẹyẹ yen le lori konisi aye koto nibe oo aofi atare kan si legbe aowa ko ewe yen bo lori mole odi jijo ti abatiri wipe ise yii tife jotan aowa du ẹ̀jẹ̀ aye koto yen sinu re Note ẹ̀jẹ̀ ẹyẹ yen kogbodo kan silẹ o toba jotan aogbe ọlọ ti afefilo ogun yii sori odo awa na mawa duro sori ibikan ti ẹsẹ wa koni kan ile ti ama filo ise yii tan aowa ro sinu ado ise yen aogbe sinu asunwon aṣọ ff aogbe ko sibiti koti ni kanle rara aoma fi oti ogogoro gidivlo ise yii ni ale kato sun Note aogbodo fi oju ri sanmo ti abatilo ise yin tan iyen tumosi wipe ako gbodo jade sita mo
(ipeayo herbalist services whatsapp only 08067248932)

21/12/2025
oso imule aji polowo ajeise yiii dara lati fi rinrin ajo 2026 fun eniti ofe gbe nkan re se ti kofe ma kigbe kosi kosi gb...
19/12/2025

oso imule aji polowo aje

ise yiii dara lati fi rinrin ajo 2026 fun eniti ofe gbe nkan re se ti kofe ma kigbe kosi kosi

gbogbo ise ti aba nse taba nlo ise yii nidi re hmmm oma dabi gba wipe ase ogun owo ni kise dandan keyan sese lo inkan eyan koto ni lari ninu aye ikoja aye ni yen awon ise kan wa tomuna doko gan but awon ise na kise ise ori Facebook koda ise eleyi gan kise ise ori Facebook osese k**a pari ise yii sori Facebook ṣùgbọ́n eni toba fese ko dm abi eniti oba fegab idi re tan ko dm ṣùgbọ́n gbigba idi re kise ofe ooo tori inkan ifa lelo miran mama wa kakiri (ipeayo herbalist services 08067248932 whatsapp only)

Ise na lo bayii

egbo tude idi meje Aidan onigun meje ọmọ olongbo ti koti laju odidi atare meta epo obo topo die àkùkọ adire pupa nla kan igba aje kan opon ifa ti won fi igi ìrókò gbẹ seere nla kan ose dudu eso laara méjèèjì oojo ewe afeloru oojo aolu olongbo yen pa aofi ewe afe loru yen tẹ́lẹ̀ ape aogbe olongbo yen le lori aoko egbo tude yen le lori aoko Aidan yen na sii pelu awon atare yen tẹ̀ le aoko epo obo yen bo mole aoko eso laara yen si aowa tunko ewe afeloru yen bo mole aofi epo pupa yika idi aro aojo ise na aolo ebu na aowa lọ aoda sori opon ifa aowa te odu ........... si aoda aniyan inkan taba fesi aopin si ona meta aopo idan mo ose aoko sinu igba aje .........

fun pipe ise yii fun awa ti anda alejo lohun eje ka dm mi kise ofe ooo fun awati aba fe kabawa se naa e dm ejoor eniti kobati setan e ma dm mio 08067248932 ipeayo

awon olori buruku miran tun ma so ọ̀rọ̀ ofo lenu kise gbogbo ise nise ori Facebook ooo nd asiri to nje kise ofe ooo oni kaluku mo wàhálà tose koto get asiri to nje oooo ire ooooooo

ipeayo herbalist services 08067248932 whatsapp only

ITUWO ASINA FUN IRIN AJO 2026 matun ba osi pelu iya ati idoti wonu odun titun mo we gbogbo ọwọ ati idoti pelu epe ati eg...
07/12/2025

ITUWO ASINA FUN IRIN AJO 2026

matun ba osi pelu iya ati idoti wonu odun titun mo
we gbogbo ọwọ ati idoti pelu epe ati egun idile kuro lara jeki gbogbo re maba 2025 lọ
taba ri ise yii se oma mu ọwọ burúkú kuro lara omatu ide osima we ara wa ni awe mo boti kere to yiii

ise yiii wa nle fun tita 10k pere lafita gbogbo ilu to aba wa ama send re fun anfani awa ti ona wa bajin si Ọ̀yọ́ alafin
ipeayo harbalist services whatsapp only( 08067248932) ekan siwa

ISE NA LO BÁYÌÍ
isawuru eyokan eso aworonso mokanla afomo ajade aolo awon eroja meteta yii papo mo ose iwe tole towa we fun ọjọ́ mẹta ao we ose yii ni ojo meta tele ara won ni osu January 1 2 3 ni dede ago mejila oru pelu adura isegum NOTE ise yii dara kawe ni ita gbangba but ti kobasi aye re funwa ale we ni abe ile naa
ipeayo harbalist services whatsapp only 08067248932

OSE ASINA ITUN IPIYAN FUN ODUN TITIN 2026fun anfani awa ti afe bere odun titun pelu iri ogo lo awa ti bii 2025 selo kote...
02/12/2025

OSE ASINA ITUN IPIYAN FUN ODUN TITIN 2026
fun anfani awa ti afe bere odun titun pelu iri ogo lo awa ti bii 2025 selo kotewa lorun afe tun ipin yen yan ejeki ani anfaani ninu awon ise yii ose kekere inu ike ff yen ọjọ́ mẹta lama fi we ni January 1 to January 3 ose yen lasan 10k lafi ta awa ti aba feni ipinu ninu 3 in 1 re etu asina, ose itun ipinyan , pelu ose awure, 30k lafita meteeta matun bere odun titun bi alai nikan se oo ati okere ni oloju jinjin ti n mu ekun sun o gbogbo ilu taba wa ama send re sibe fun wa koda koje wipe loke okun lawa
ejeki aba oludasile egbe sọ̀rọ̀( ipeayo harbalist services )whatsapp only 08067248932
ejoor ema wa romi lejo oo moti ko iye re si ooo eniti koba ti setan koma dm mioooo
aonise oribu oooooo
Ire ooooooo
odun ayo lao se ooooo

ASEJE OSHOLE AGBA YEKUYEKU aseje yii dara gan fun eniti obari se owo nla ni aseje yii ma n muwa ti eyan bani imule lara ...
27/11/2025

ASEJE OSHOLE AGBA YEKUYEKU

aseje yii dara gan fun eniti obari se owo nla ni aseje yii ma n muwa ti eyan bani imule lara tabi ti ara eyan bamo dada Olódùmarè ngbo million loma muwa fun eyan ki ara etan tun wa doti gan asima ri owo kise aseje lasan

akiyesi
eroja towa okay ni kejeki aloo kasi kiye si awon eroja yen kari wipe oju lowo eroja ni won ta fun wa abiki awon ti wọn mo nipa ise yii bawa se o
Note
mio fe ibere kankan lori ise yii o tiki base ise re mawule dawo le o( ipeayo harbalist services 08067248932 whatsapp only)

ise na lo báyìí
ikode merin, iye agbe merin,iye aluko merin ,ewe tolale hu ninu odo eyi keyi aowa ja ewe na ejeki alo awon eroja yii ni ototo pelu iyere 16 aofi omi odo ti ati ja ewe yen die si awon nkan ti alo yẹn aowa ge eran agutan si 16 aoko sinu ikoko aseje aowa ko awon eroja yen si leyo kokan aose laseje lepo niyo aowa so sori osuka a*o ff aowa se adura sii owo alafia wa lamafije aseje yen aowa mu omi aye si lori hmmmm

ikilo
k**a ni ibalopo laarin ojo meta oo kasi mamu omi aye dada larin ojo meta yen
ipeayo harbalist services 08067248932 whatsapp only

OSO OLAoro isaju ibiti abatise laati ji lodifa fun ise oso yii kise ise ori Facebook opó ise na la nfi si ori afẹ́fẹ́ ti...
20/11/2025

OSO OLA
oro isaju
ibiti abatise laati ji lodifa fun ise oso yii kise ise ori Facebook opó ise na la nfi si ori afẹ́fẹ́ ti awa na mope kise ise ori afẹ́fẹ́ ṣùgbọ́n ki awon eyan le maje anfaani ise gidi láfi nse be sibe ọpọlọpọ nani komo oore rara ibi ise yii aomo awon ti wọn mo iyi oogun ati ona ti angba gba ise gidi ogun nla kise ise to rọrùn láti rí but awa mafi sile fun awon ti wọn mo iyi re

ise yiii

oso ni ise yiii kise oshole o iyato wa laarin awon mejeji atiye awon ojogbon sha iwo ti obada ọwọ le ise yii ti osiri se moki eh kú orire ooooo mofi Olódùmarè bura lori ise yiii omadi olowo lenu ise re ona re mala aye mamo eh nile yii ati loke okun o sure funmi gan ni Ọlọ́run Olódùmarè ngbo.

ISE NA LO BÁYÌÍ
ijapa nla kan ìgbín nla meta eye kowe tako tabo ewe kasan 201 ọpọlọpọ ewe itiponola ewe apada 201 odidi atare kan a*o ff ilaji opa ẹyẹlé ff kan ẹyẹlé dd kan aofi a*o funfun yen ran asunwon aogbe ijapa pelu ìgbín meteeta yen sinu re aoso lenu pa aogbe sinu ape aoko kowe mejeji si lori aoko awon ewe yen le lori ṣùgbọ́n ewe apda lomawa loke aofi odidi atare kan si odi jíjó ti ogun na bati joo dada aowa mu ẹyẹlé dd leses mejeji dani aofi yika ikoko ogun ta njo lowo yen lemesan fun ọkùnrin emeje fun obinrin pelu àníyàn ise ti enina nse bí otife bii otife ki aye mo ohun lori re nilu re ati loke okun bí otife mari owo lona kona leyin eleyi aowa si ideri ape yen aoju ẹyẹlé yen sinu re loye ao de pada toba jotan aolo kuna aoro ogun yii sinu sere Sango aowa fi ẹyẹlé ff toku yen bo sere yen ao nile irun re mo lara o ẹ̀jẹ̀ re nikan ni ama fira ara sere yen aotu mejo mejo nibi iye apa re kokan totun ati tosi aofi owu ff di papo ohun laofise èdìdì enu ado yen ti eje ara sere yen bati gbe dada aogbe sinu apo a*o ff aogbe si aye ọwọ́ ara ẹyẹlé toku yen aolo bo mole

lilo ise yiii
sara ise yiii
ojo ti aoma lo ise yiii
eniti oba nilo ise yii ko message me lori whatsapp Note enina masan 10k ki nto yoda re fun o ma 08067248932 iwo toba sife kaba eh se dm ma dm ti obati setan

IMULE ELEMERE 🦅🦅🦅 imule yii wa fun awa ti abani afokan sun ati ni lari ninu aye mofi Olódùmarè mare bura lori imule yii ...
17/11/2025

IMULE ELEMERE 🦅🦅🦅

imule yii wa fun awa ti abani afokan sun ati ni lari ninu aye mofi Olódùmarè mare bura lori imule yii eni tobalo ti koni lari laye aje wipe atiko wipe enina kolese ori re ninu aye niyen ọpọlọpọ ni imule towa laye o ṣùgbọ́n imule eleyi ni oso atila ninu awon agba gangan ni won ma sanu wa ti kosi si ìpalára kankan nibe
IKILO PATAKI
iwo ti obada ara re loju ma dawole ise yii because kíkọ ni mimọ ooo nd ìwọ ti kibase ise re ni kaja ewe kaja egbo madawo le ooo nd ọpọlọpọ eyan na lo nja ewe to n wa egbo ti wo o mo nipa rẹ rara because won o kọ won kan rí ìwé lasan ni won sọ ara wọn di ologun ori aye lujara emako ba ara yin oo ise yii kise fun iru yin oooo

EJOOR
ki ẹni Kénì mawa sori dm me lati tun wa bere alaye kankan o moma gbe iru eni be sepe nio iwo ti obasi fe kaba eh se ti kobati sii owo toma fise lowo re mawa sori dm mio oo (ipeayo harbalist services 08067248932 whatsapp only)

ISE NA LO BÁYÌÍ

ewure ti oni oyun ti oyun re siti dagba dada aowa pa ewure náà aogbe ọmọ inu rẹ jade aodu ọmọ re yen sinu agbada ki agbada yen je titun kosi tobi dada aowa pa ni panṣa lati idi ao wako awon eroja yisi lati ibi pansa yen obi ipa 16 obi ifin 16 orogbo 16 oga oye 16 ọpọlọ 16 odidi atare aja 16 iye agbe iye aluko ikode iye igun iye lekeleke ki gbogbo awon iye yen na je 16 aowa ko gbogbo owo ta na si enu ọmọ ewure yen aowa fi awo igala we gèlè fun aofi epo Pupa yii aro yipo aowa jo aoro sini ado atoo aopa eye etu bo ado yen hmmmm
Note atari Àjànàkú ni ise yio kise eru omode ooo ( ipeayo harbalist services 08067248932)

amaba lilo re pade ninu comment ire oooo

ma wa sori dm me fun alaye ise yi mo oo iwo tobati mo nipa re madawo le o komafi owo re sofo lasan ooo eniti kobati setan atise ise yii mawa sori dm mi oooo ipeayo harbalist services 08067248932 whatsapp only

10/11/2025

Address

Kwra Ilorin
Oyo

Telephone

+2348067248932

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Awon Ogun iwosan Ara posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram