Atunse pelu EWE ATI EGBO

Atunse pelu EWE ATI EGBO Here we I'll and free peoples from all spiritual problems

24/06/2024

AKU ASEKU ATI ALAJA ODUN OOO

02/12/2023

kini nkan ti mo le fi ran eyin eyan mi lowo

02/12/2023

Ojumo ire Aku ojo meji meta asi ku ipalemo Qdun

29/07/2023

Can you accept my invitation so I can get a free gift worth up to $80? 🎁

Pls join this link for more.
22/06/2023

Pls join this link for more.

WhatsApp Group Invite

05/04/2023

Aku Oungbe

03/04/2023

Will be back and better soon

21/12/2021

To make people’s stay away from bo***ge

APE IFERAN TOSISE GIDI GAN TIA TI CONFIRM DAADAKOSI ENITI KO LE LOO, KODA AWON WORKING BOY TON TEKA NAA LE LOOObi gbanja...
12/05/2021

APE IFERAN TOSISE GIDI GAN TIA TI CONFIRM DAADA
KOSI ENITI KO LE LOO, KODA AWON WORKING BOY TON TEKA NAA LE LOO

Obi gbanja oloju meji funfun, ao la si meji, ao fi abere(needle)te Ifa ejiogbe soju awe obi kan, ao wa mu eyo atare mejo, ao kii soju ejiogbe tia fi abere te yen leyokookan,
Tio bati di ago kan oru ti eniti a fe sa iseyii fun bati sun, ao wa bosi enu ona sitting room to jasi ita, ao wa bu iyo die si atelewo osi wa, ao wa gbe obi tia te ejiogbe si lori, Ihoho omoluabi lao sise yii lago kan oru yen, o wafi owo otun wa mu ilekun sitting room yen dani

OHUN RE:
Ao se Ha3x,
Amororo loruko tia npe oko, aronigbebikan jifa loruko tia npe obo, afojuboju loruko tia npe omidan weere, ile(house) kii di t**i ki aala ma wonu re, Ejiogbe ooo, gbe aworan mi loba L omo L kori mi bayii bayii, tio badi ojo jeki kio pemi pe ohun ti nife mi, Ao wa se adura nkan tia nfe si daada, ao wa da gbogbo nkan towa lowo wa yii senu pata ati iyo ati obi, ao je, ao wa fon eyiti owa lenu wa sita lemeta, Ao wa pa ilekun yen de leekanna, Ilekun tia pade yen loma ji nibi ti o wa. Ao wa pada lo sun.
Ise todaju ni

16/02/2021

AYETA AWON JAGUNJAGUN AYEATIJO

Ewe bomubomu meta
Orogbo tutu meta
Eyin ibile meta
Ewe ailu eyo meta
Atare aja kan

A o Jo gbogbo awon eroja papo
A o wa lo kunna
A o wa fi singbere lati iwaju ori de ibadi
Eyan meji si meta lo le lo

Ti ba fe danwo
E bu die sinu handkerchief white
E o ta nikoko
E So mo orun aja
Ke yinbo fun
Ko ni wole
iseyi jaa ole . Ojo tio ba gbero lati do Jake ni ibon mapa e lase edumare Amin

16/02/2021

IMULE AWỌN AGBA ATA MATASE.
Ao lowa òkété ayé kan ao pa ao ko ifun rẹ. Ifun rẹ yi laolomo epo obo gidi ewe ajekobale. Ao wagun papo mo odidi ataare kan. Leyin eyi ao ko ọsẹ yi sinú ike funfun kan. Ao gbe pamo fún odidi ojó mẹta lẹyìn ọjọ ti ao bẹrẹ sini wẹ ọsẹ yi lale sun.
Òkété tiako ifun rẹ yi ao lori monle yíò kọjú sí qiblah.

Ọsẹ yi wúlò púpọ̀ fún atude asina ebe awon agba pẹlu IMULE won.

MOKI ẹyin àgbàlagbà oooo

15/02/2021

EYONU AWON AGBA TO COMFIRM

MEJI META LOGUN NIGBAMI

OJO TOBA NI ASEJE KAN ABI ISE KAN TOSARE FELO
SARE BAMI WE OSE EYONU YIII
O LE SE KOPO KOMA WEEE KOSI WHALA NBEEE

EROJA RREE

EWE AJEOBALE TOPON SORI IGI
IMI OJO
EPO OBO
EO GUN MOSE EO WE LALE SUN

ODAJU

Address

Sango Otta

Opening Hours

Monday 09:00 - 19:00
Tuesday 09:00 - 19:00
Wednesday 09:00 - 19:00
Thursday 09:00 - 19:00
Friday 10:00 - 17:00
Saturday 11:00 - 16:00

Telephone

+2348030670754

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Atunse pelu EWE ATI EGBO posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram